Anthony Joshua àti Deontay Wilder lè wọ̀yá ìjà lórí $50m

Joshua Anthony pẹ̀lú àwọn ife ẹ̀yẹ rẹ̀

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Kìí ṣe ẹrù ọmọdé láti gba WBO, IBF, àti WBA

Níbi tí erin méjì bá ti jà......

Wilder Deontay pẹ́lù àmì WBC

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Tí oògùn ẹni bá dá ni lójú, áà fi gbárí ni

Njẹ́ Anthony yóò gbà láti bá Wilder jà bi?

Anthony Joshua, ọmọ ọdun méjìdínlógún tó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹ̀yẹ níbi ìjà káàkiri kò tíì gbà láti kojú Wilder.

Ṣe $50m tó owó tí o lè jàfún bí?

Ọrọ̀ ìjà ju owó lọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: