Kò ṣe é mà gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é mà gbọ̀ ọ́
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Afurasi Aafa Abdulrahman Bello ti wọn fẹsun kan pe o sẹkupa Yetunde Lawal n'Ilorin tun foju bale ẹjọ lonii

Abdulrahman to n jẹjọ pẹlu afurasi mẹrin mii rọ adajọ pe ko fawọn ọkunrin mẹrin naa silẹ tori oun nikan loun mọ nipa iṣẹlẹ iku Yetunde

Ki ni adajọ wa sọ?

Idahun si ibeere rẹ wa lori Ikanni BBC Yoruba

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Awọn eeyan to padanu ẹmi wọn nibi ile alaja mẹta to dawo lagbegbe Lekki niluu Eko ti di mẹrin bayii

Yatọ si eeyan mẹrinla mi-in to farapa, agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ṣalaye pe

Lalẹ Ọjọru lawọn oṣiṣẹ iṣẹlẹ pajawiri kọkọ yọ oku eeyan meji nibi ti ile ti wo ọhun ki wọn tun to yọ meji mii jade laarọ Ọjọbọ

Alaye wa lori BBC.Com/Yoruba

''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''

Natasha lòdì sòfin ile pẹlu bí ó ṣe buwọ́lu ìwé ẹ̀sùn tó fi pé Akpabio lẹ́jọ́ lo jẹ ki a yi ẹsun rẹ danu

Ìgbìmọ̀ tó ń ṣewadi ẹsun iyọlẹnu fun ibalopọ ti Natasha Apoti-Uduaghan fi kan aarẹ ile aṣofin agba l'Abuja Sẹnẹtọ Godswill Akpabio sọ pe ẹlomiran lo yẹ ko buwọlu iwe ẹsun naa