Agbẹjọ́rò Abdullateef Lanre Abdullahi sọ pàtàkì ìbálòpọ̀ àti ìmọ́tótó láàrin lọ́kọláya

Àkọlé fídíò, Agbẹjọ́rò Abdullateef Lanre Abdullahi sọ pàtàkì ìbálòpọ̀ àti ìmọ́tótó láàrin lọ́kọláya

O ṣe pataki ki lọkọlaya maa ba ara wọn sọrọ daadaa- Alfa Lanre Abdullahi

Akọsẹmọṣe nipa ibalopo láàrin lọkọlaya ati onimọkikun nipa ẹsin Islam, to tun jẹ agbẹjọro, Abdullateef Lanre Abdullahi sọrọ ni kikun nipa ona ti ọkọ fi gbọdọ fi maa wu aya rẹ

O sọrọ nipa pataki ibaraẹnisọri laarin lokolaya ki wọn fi le gbadun ifẹ ara wọn.

Imoran wo ni Alfa Lanre gba awọn eeyan?

Mọ sii nipa awọn igbesẹ to yẹ ki tọkọtaya to yẹ ki lokolaya gbe lati yanju aawọ inu ibalopọ ki igabdun le wa fun awọn mejeeji.

Bakan naa lo sọ nipa ọna itọju abẹ ati ara laiyọ awọn awọtẹlẹ silẹ rara gẹgẹ bii ohun to n wu ọkọ ati iyawo