Kò sí ńkan ti ọkùnrin ń ṣe tí obìnrin kò le ṣe, kódà, mo ń tún 'Pumping Machine'- Afusat Adeniyi
Iṣe Ajogunba wo ni ẹ ba lọwọ awọn Obi yin?
Ifọkansin ati itẹpamọṣẹ lo gbe mi de aaye ti mo wa yi- Onimọ ẹrọ Afusat Adeniyi
Arabinrin yii ni akọsẹmọṣẹ to n tun gbogbo ohun eelo ati ẹrọ to n lo kọ́ìlì ṣe.
Afusat salaye bi o ṣe kọṣẹ yii lọdọ baba rẹ to jẹ jorinjorin wẹ́dà ati aburo baba rẹ to jẹ́ eni to n tun ohun eelo to n lo kọili ṣe.
- 'Wàláhì láàrín ọdún kan péré tí mo bá dé Aso Rock, ẹ wo ǹkan tí yóò yí bírí ní Nàìjíríà'
- Mo rọ̀ lápá àti ẹsẹ̀ lẹ́yìn tí mo lá àlá pé àgbébọ̀ adìẹ sá mi jẹ lójú oorun
- Ta ni Yorùbá ń pè ní Abọ́bakú?
- Aláàfin àti Ọba ilẹ̀ Yorùbá márùn-ún mìí tó wàjà láàrin oṣù márùn-ùn péré
- Bí mo ṣe máa rí N100m tí mo fẹ́ fi gba fọ́ọ̀mù APC rèé...
- Oru tí olóríibú máa ń di olóríire ni "Laylatul Qadr", tóo bá bẹ Ọlọ́hun, orú agbára gidi ni - Akeugbagold
Kini Afusat tun sọ?
Arabinrin Afusat tun parọwa fun awọn Obi ati Alagbatọ lati tubọ kọ ọmọ.
O ni ki wọn je ki wọn kọ iṣẹ ọwọ mọ ti iwe ti wọn n ka.
Bakan naa lo sọrọ nipa irinajo aye rẹ.
- Wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré Yorùbá tí kìí ṣe ọmọ káàárọ̀ oòjíire
- Ǹjẹ́ o mọ àwọn òṣèré bí Oyin Adejọbi, Funmi Martins àtàwọn míì tó ti dágbére fáyé?
- Ìtàn ìgbé ayé Isola Ogunsola 'I-sho Pepper', ògbóǹtagí òṣèré tíátà tó s'eré Yorùbá yíká Nàìjíríà
- Kí ló wà ní ìdí igbá tí àwọn olorì Aláàfin máa ń tí lóde Ọ̀yọ̀
- Ìjà Awolowo, Akintola àti ogun 'Wẹtiẹ', ẹ̀kọ́ wo ló kọ́ wa?
- Igbo Olodumare rèé, níbi tí Ìgbín ti tóbi ju Ìjàpá lọ
- Ìdílé márùn-ún tó gbajúmọ̀ fún òwò ẹrú nílẹ̀ Yorùbá


