Female Carpenter: Fatia Garu ní ọ̀pọ̀ èèyàn ni kìí gbàgbọ́ pé obìnrin ló ń ṣiṣẹ́ Káfíńtà
Isẹ Kafinta kii se isẹ ta mọ awọn obinrin mọ bikose isẹ ọkunrin amọ lasiko yii awọn obinrin naa ti n sisẹ ọhun.
Eyi si lo fidi rẹ mulẹ pe ko si ohun ti ọkunrin n se, tawọn obinrin ko le se.
Ọkan ninu awọn obinrin to yan isẹ kafinta laayo ni bẹẹ ni Fatia Garu ti ọpọ mọ si Lady G.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- "Bàbá mi lòdì sí iṣẹ́ aṣerunlọ́sọ̀ọ́ tí mò ń ṣe àmọ́ lónìí, ó ń mú owó ńlá wá fún mi"
- Awọn gbajumọ akọrin ati oṣere tiata obinrin Naijiria sọ nipa idẹyẹsi lọwọ awọn ọkunrin
- Aṣọ ni mò ń tà tẹ́lẹ̀, ìgbélé Covid-19 ló sọ mí di awakọ̀ kabúkabú - Adebunmi Adeyeye
- Mọrèmi Àjàṣorò, akọni obìnrin tó gba Ilé Ifẹ̀ sílẹ̀ lóko ẹrú
- Wo àwọn obìnrin tó ń bímọ láì sùn ti ọkùnrin ní àgbáyé
- Òkú obìnrin tí mò ń lọ wẹ̀ yọ sí mi, ohun tó sọ rèé - Agbókùújó
- Wo ohun tó ṣe kí àtọ̀ rẹ fi ní agbára láti di ọmọ
- Ìtàn tó rọ̀ mọ́ òwe ‘aṣọ kò bá Ọ́mọ́yẹ mọ́...’ rèé
Nigba to n ba BBC Yoruba sọrọ, Lady G ni ọkọ oun lo se iwuri fun oun lati lọ kọ isẹ naa.
O ni isẹ asọ tita lo wu oun tẹlẹ amọ nibayii, oun ko kabamọ pe oun kọ isẹ naa.
Bakan naa ni ọkọ rẹ salaye pe ọpọ eeyan ni ko ri owo jẹun, debi pe wọn yoo ra asọ, idi si ree ti oun fi gba aya oun nimọran lati lọ kọ isẹ ọwọ.
O salaye pe lasiko yii, isẹ ọwọ pe ju okoowo lọ.
Obinrin Kafinta naa wa gba awọn ọkunrin nimọran lati maa sugba iyawo ninu ohunkohun ti wọn ba dawọle.





