Akomolede ati Asa: Ọ̀rọ̀ Asopò ni á ń gbéyẹ̀wò pẹ̀lú Arabìnrin Tope Atoyebi láti Ilorin

Àkọlé fídíò, Akomolede ati Asa: Ọ̀rọ̀ Asopò ni á ń gbéyẹ̀wò pẹ̀lú Arabìnrin Tope Atoyebi láti Ilorin

Mọ̀ sii nipa iṣẹ ti Oro Asopo n ṣe ninu gbolohun ede Yoruba- Tope Atoyebi

Lori eto Akomolede ati Asa lori BBc Yoruba ni a wa yii.

Oro Asopọ ni koko girama ni koko ti a n gbe yẹwo loni lori eto naa.

Kini ọrọ Asopo?

Iṣẹ wo lo n ṣe ninu gbolohun?

Akomoled

Bawo lo ṣe le da a mọ ninu gbolohun?

Awọn ibeere yii ati omiran ni Arabinrin Tope Atoyebi lati ile ẹkọ Emmanuel Baptist College, Tanke ni ilu Ilorin ni ipinlẹ Kwara ni aarin gbungbun Naijiria.