Akomolede àti Aṣa: Olùkọ́ Olajide láti Ẹdẹ ló ṣàlàyé nípa Awẹ́ Gbólóhùn fún wa ní kíkún
Omo naa sare nigba to ri eegun- Arabinrin Bisola Bose Olajide
Eto Akomolede ati Aṣa lori BBC Yoruba ni o tun jade loni.
Arabinrin Bisola Bose Olajide lati ile ẹkọ Adeleke University High School ni Ilu Ede ni ipinlẹ oṣun ni guusu iwọ oorun Naijiria ni olukọ wa fun toni.
Awẹ Gbolohun ni koko ti a n gbe yẹwo.
Eto Akomolede ati Asa jẹ eyi ti a n fowosowopọ ṣe pẹlu ẹgbẹ Akomolede Naijiria ati ẹgbẹ Onimọ Yoruba YSAN.
Iṣe wo ni awẹ gbolohun n ṣe ninu ede Yoruba.
Bawo ni a ṣe le lo awọn ọrọ kọọkan?
Mọ sii nipa oriki awẹ gbolohun, iṣẹ wo lo n ṣe, iṣẹ ti wọn n ṣe





