Adewole Quyum: Ọdún10 ni mo ti ń kọ́ 'welder' mo ti ṣe ọ̀kadà tó ń lo 'generator'

Àkọlé fídíò, Adewole Quyum: Ọdún10 ni mo ti ń kọ́ 'welder' mo ti ṣe ọ̀kadà tó ń lo 'generator'
Adewole Quyum
Àkọlé àwòrán, Adewole Quyum

Egberun marindinlogoji ni mo fi sọ kẹkẹ di ọkada- Quyum Adewole

Quyum Adewole jẹ ọdọmọde ẹni ọdun mẹrindinlogun to n fi iṣẹ jorinjprin dara.

O ni oun bẹrẹ si ni kọ iṣẹ jorinjorin lati ọmọ ọdun mẹwaa.

Nigba ti Baba oun fi sẹnu ẹkọṣẹ.

Adewole Quyum

Kini Quyum tun sọ?

Bakan naa ni Adewole Quyum tun gba awọn ọdọmode bii tirẹ ni imọran.

O ni pe osu marun un ni oun fi sọ kẹkẹ naa di alupupu.

Ati pe, ẹgbẹrun marun un dinlogoji ni oun lo lati fi ra awọn nkan pẹẹpẹẹ to fi ṣiṣẹ nsiyi.