Tunbosun Odunsin: Ẹlẹ́dàá ló fún mi ní tálẹǹtì ẹ̀kún sísun ní ìrọ̀rùn nínú eré tíátà
Gbajugbaja osere tiata kan Olatunbosun Odunsi, ti salaye pe talẹnti ti Ẹlẹda fun oun ni lati maa sọkun ni irọrun ninu ere tiata.
Odunsin, lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ, salaye pe akọsẹmọsẹ osere tiata ni oun, tawọn olootu ati oludari ere si maa n wa oun kiri tori talẹnti ẹkun sisun ti oun ni.
Bakan naa lo salaye akọsẹmọsẹ osere tiata gbọdọ le se ipokipo ti wọn ba fun ninu ere sise, is ti wọn ba si fun oun ni oun maa n se daada.
- Òṣèré méjì yìí ń fi ẹ̀wọ̀n runmú tóríi fíìmù "Ife" táwọn obìnrin ń bá ara wọn lòpọ̀
- Ó ṣe mí ní àánú fún ọmọ Yorùbá tí kò le sọ èdè abínibí rẹ́ - Ọmọ Igbo Chukwuka
- Mo ti di 'Millionaire' kí n tó pé 18 rárá, ìdí iṣẹ́ arìnrìnoge ni mo ti di òṣèré- Omotola Jalade Ekeinde
- Mò ń wá olè tó jí nńkan ní ọọ́físì mi, ẹ̀bùn owó iyebíye rèé - Afeez Eniola
- Wo àwọn ìlúmọ̀ọ́ká tó ṣe ìgbéyàwó ní ọdún 2020 yìí
- Allwell Ademola sọ̀rọ̀ lórí ìdí tó fi ń ṣe ọjọ́ ìbí 35 lọ́dọọdún
- Ẹ gbà mí o, wọ́n ti ń fi kóló mi kó àwọn èèyàn lómi ọbẹ̀ jẹ- Tawa Ajisefinni
O ni wọn kii pe oun lati wa se ipo olowo nitori oun ko yọ ikun bii olowo rara amọ sa, wọn maa n pe oun lati ko ipa bii ọlọpaa ati adajọ ninu ere.
Osere tiata naa, ti ọpọ eeyan tun mọ si Paadi Mikailu tun salaye pe oun maa n sọ awọn eeyan ti nnkan ba sẹlẹ si loju aye lati mọ ihuwasi wọn.
O fikun pe iru iwa yii ni oun maa n gbe wọ nigba kiigba ti wsn ba gbe iru ipa bẹẹ fun oun.
- Igbo Olodumare rèé, níbi tí Ìgbín ti tóbi ju Ìjàpá lọ
- Ìdílé márùn-ún tó gbajúmọ̀ fún òwò ẹrú nílẹ̀ Yorùbá
- Wo ìtàn ayé gbajúmọ̀ adigunjalè méje nílẹ̀ Yorùbá
- Jimoh Odutola, akọni oníṣòwò tí kò kàwé, àmọ́ táwọn Ààrẹ orílẹ̀-èdè ń ké sí láti wá dá iléesẹ́
- Njẹ́ o mọ̀ pé bíi ọdún 700 sẹ́yìn ni wọ́n ti ń bọ Osun-Osogbo? Mọ̀ síi nípa ìtàn ojúbọ̀ nàá
- Adunni Olorisa, obìnrin òyìnbó tó di ìyàwó òrìṣà nílẹ̀ Yorùbá títí di ọjọ́ ogbó
- Alimotu Pelewura, Ìyálọ́jà akọ́kọ́ l’Eko tó mi amúnisìn àti ìjọba tìtì

