Celebrity wedding: Wo àwọn ìlúmọ̀ọ́ká tó ṣe ìgbéyàwó ní ọdún 2020 yìí

Kayode ati Oluwafunmilayo

Oríṣun àwòrán, Instagram/officialkayodeadebayo

Iyawo dun lọsingin, ọkọ tun mi gbe. Adia fun awọn ilumọọka kan ti wọn ṣe igbeyawo lọdun 2020 yii.

Bo tilẹ jẹ pe, coronavirus ṣe awọn eeyan mọle, iṣede covid-19 ko dena mọ awọn ololufẹ yii lati di tọkọ taya.

Wọnyi ni awọn gbajumọ to ṣe igbeyawo alarede lọdun 2020 yii.

Adewale Adeleke ati Kani Ekanem

Adewale Adeleke ti inagijẹ rẹ n jẹ ''ChairmanHKN'' nin ẹgbọn gbajugbaja olorin takasufe, Davido.

Oun ati Davido jẹ ọmọbibi inu Adedeji Adeleke to lowo bii ṣẹkẹrẹ.

Adewale ati Kani

Oríṣun àwòrán, Instagram/chairmanhkn

Ninu oṣu keje ọdun 2019 ni Adewale dẹnu ifẹ kọ Kani eyi ti ọmọbinrin naa si ni ko si ṣiṣe ko ṣai ṣe, Adewale loun yoo ba lọ.

Gbogbo iyoku ti di itan bayii, Adewale ati Kani ti di lọkọlaya.

Adewale ati Kani

Oríṣun àwòrán, Instagram/chairmanhkn

Sandra Ikeji ati Arinze Samuel

Ọjọ kọkanla oṣu kinni ọdun 2020 ni Sandra Ikeji di aya lọọdẹ ọkọ rẹ, Arinze Samuel.

Sandra ati Arinze

Oríṣun àwòrán, Instagram/sandraikeji

Àkọlé fídíò, Yollywood: Sinimá Ajé Ọjà tún so Fathia àti Saheed Balogun pọ̀ nínú Sinimá
Sandra ati Arinze

Oríṣun àwòrán, Instagram/sansraikeji

Anita Joseph ati MC Fish

Ọjọ kẹrinla oṣu keji ọdun 2020 ni Anita Joseph ati MC Fish ṣe igbeyawo niluu Eko.

Anita ati MC FIsh

Oríṣun àwòrán, Instagram/anitajoseph

Anita ati MC FIsh

Oríṣun àwòrán, Instagram/anita joseph

Kayode Adebayo ati Oluwafunmilayo Adebayo

Ọjọ keje oṣu kẹta ni Kayode Adebayo ṣe igbeyawo ti wọn si di lọkọ laya.

Kayode ati Oluwafunmilayo

Oríṣun àwòrán, Instagram/officialkayodebowale

Kayode ati Oluwafunmilayo

Oríṣun àwòrán, Instagram/officialkayodeadebayo

Seilat Adebowale ati Adeyemo Olalekan

Seliat ati Adeyemo

Oríṣun àwòrán, Instagram/seliat adebowale

Seliat ati Adeyemo

Oríṣun àwòrán, Instagram/seliat adebowale