Sleep paralysis: Kò sí òkú tàbí aǹjọ̀nú tó n lé ọ lójú oorun- Olajide Obembe
Ma ṣe lọ sile alagbo, tabi tan abẹla tabi ọdọ adahunṣe lori pe wọn n le ẹ loju oorun- Dokita Obembe Olajide
Oriṣiiriṣii nkan ni awọn eeyan maa n sọ pe o n ṣe wọn alti oju oorun wa si oju aye.
Bí ọpọ ṣe n sọ pe eegun n le wọn loju oorun, ni awọn mii maa n sọ pe wọn n rin wọn mọle tabi ga wọn lọrun lati oju oorun.
Elomii a tun sọ pe o dabi pe oku tabi alujonnu n rin ninu ile oun ati ninu iyara ibusun oun.
Nigba mii, awọn kan a tun sọ pe awon n ni ajọsepọ pẹlu ẹlomii lati oju oorun wa.
- Pẹ̀lú gbogbo rògbòdìyàn tó ń ṣẹlẹ̀ ní Nàìjíríà, APC kójú òṣùwọ̀n láti borí ìdìbò 2023- Adamu
- Ṣé òótọ́ lẹ̀sùn tí Adeleke fi kan ìjọba Oyetola pé Ó ń kó owó ìjọba ìbílẹ̀ pamọ́ lọ́nà tí kò bófinmu-
- Wo àwọn nọ́mbà ìpè agbófinró tó yẹ kò mọ̀, èyí tó pè tí ìkọlù agbébọn bá dé
- Irú ọmọ wo ní Yorùbá ń pè ní Olúgbódi?
- Wọ́n sọ Babalawo méjì sí gbàga fún ẹ̀sùn jìbìtì £29,000 ni Eko
- Bí ikú ilé kò bá pani...ìkìlọ̀ rèé fún ẹ̀yin ọmọ Yorùbá tí ẹ n gbàbọ̀dè f'ájínigbé- Oba Francis Alao
- Ìjọba Eko tún ti gbẹ́sẹ̀ lé ìgbòkègbodò Okada láwọn ìjọba ìbílẹ̀ míràn
- Wo bí àṣà ìbálé lálẹ́ ìgbeyàwó ṣe ń dọdẹ àwọn obìnrin òde òní kiri
- Àwọn aya Yekeen Ajileye ló fa ìpinyà láàrin wa débi pé mo fẹ́ pa ara mi - Abija
Dokita Olajide Obembe to jẹ akọṣẹmọṣẹ ninu iṣẹiṣegun ati itọju ọpọlọ gbalejo BBC.
O salaye awọn nkan to n ṣokunfa gbogbo iṣẹlẹ yii ninu ọpọlọ eeyan ati ọna abayọ.
- Kìí ṣe gbogbo ohun tí dókìtà ni kí n má jẹ torí àìsàn jẹjẹrẹ ni mo tẹ̀lé- Soyinka
- Mọ̀ síi nípa irú oúnjẹ tó ń fa àrùn jẹjẹrẹ lára
- Owó oṣù 'Professor' ju ti 'Perm Sec' lọ nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní 1963- Emeritus Ayo Bamgbose
- Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
- Egungun Oloolu ti ilẹ̀ Ibadan fojú han aráyé! Gbọ́ àwọn ǹkan tó ń dẹ́rù ba obìnrin, ọmọde nípa rẹ̀ àti èèwọ̀ rẹ̀
- A kò lè sọ pé Haram ní 'Oral Sex' nínú Islam ṣùgbọ́n Makrooh ni- Aafa Abdullateef
- Òṣèré tíátà, ẹ má jẹ́ kí àbùkù wọ ìlàkàkà yín láti kó ọrọ̀ jọ - Ajirebi
Bakan naa ni BBC ba awọn to n la isoro yii koja bii ọgbẹni Samuel Oluwafemi sọrọ lati ṣapejuwe bi o se n sẹlẹ si wọn gangan.
Dokita Obembe gba awọn eeyan nimọran lati maṣe daamu lọ sile alagbo bikoṣe ki wọn gba ileewosan lọ fun itọju to peye.