Pregnant dead mummy: Ṣé ẹ ti gbọ́ nípa òkú gbígbẹ́ tí wọ́n ṣì bá oyún nínú rẹ̀?
Ẹgbẹ awọn onimọ Sayẹnsi to maa n wu nkan jade ninu ilẹ ti ṣawari eeyan akọkọ ti wọn ṣi ba oyun ninu rẹ lẹyin to ti ku fun ọpọlọpọ ọdun.
Awọn onimọ sayẹnsi ara Poland yii ti wọn pe orukọ akanṣe awari ti wọn ṣe ni "Warsaw Mummies Project" wu eyi jade nigba ti wọn n ṣe ayẹwo kikun ninu ẹrọ arinurode (scan machine) lori oku to ti pe ẹgbẹrun meji ọdun.
- Ẹ fi Sunday Ìgbòho sílẹ, ǹkan tí ìjọba Nàìjíríà bàjẹ́ ló ń gbìyànjú àti túnṣé; Ìjọba àpapọ̀ ní láti tọrọ àforíjì lọ́wọ́ rẹ̀ - Wole Soyinka
- Sunday Igboho kọ̀wé sí ìjọba àpapọ̀, o ní dandan kí wọn sàn owó gbà má bínú ₦500m
- Ẹ má gbàgbé láti mú "Candle" yín wá síbi ètò ìsínkú Wòlíì TB Joshua tí yóò bẹ̀rẹ̀ lọ́la - Ìjọ SCOAN
- 'Ṣọ́ọ̀bù ìyá rẹ̀ ní Jumoke wá tí ìbọn ọlọ́pàá ti pa á lásìkò ìwọ́de Yoruba Nation ní Ojota'
- Wo ohun tó yẹ kí o ṣe sí ojú abẹ́ rẹ, ''vagina'' lẹ́yìn ìbálòpọ̀
- Àwọn ọmọ ìkókó níléèwòsàn kàgbákò agbébọn! Wọ́n jí wọn gbé pẹ̀lú nọ́ọ̀sì
- Ó tún ti ṣẹlẹ̀! Agbébọn tún jí àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ Baptist kan gbé
- Mo ti yọ'wọ́ lọ́rọ̀ òṣèlú Nàìjíríà, tẹ́ẹ bá ń gbọ́ pé Obasanjo dá ẹgbẹ́ òṣèlú sílẹ̀, "ẹyẹẹ̀ mi kọ́"!
Iṣẹ akanṣe yii bẹrẹ lọdun 2015 ti wọn si n fi oriṣiriṣi ẹrọ ṣayẹwo awọn oku ọlọjọ pipẹ ti wọn ko jọ si ile ti wọn n ko nkan iṣẹmbaye si ni Warsaw. Lati ọọrundunrun 19th Century ni wọn ti gbe oku arabinrin naa wa si Poland.
Wọn ni ọjọ ori arabinrin yii ni pato ko lee ju ọdun ogun si ọgbọn lọ. Amọ wọn ni awọn oku rẹ ni "abami iyalọmọ" tori nkan tawọn ba nidii ayẹwo ti awọn ṣe fun un.
- "DSS yin ọta ìbọn 48 sí Adogan, kò sì kú, ni wọn bá fi ọmọ odó fọ lórí"
- Wo ohun tó yẹ ko mọ̀ nípa Saheed Adigun (Adogan) tó kú nílé Sunday Igboho
- Bí Igboho kò bá jáde, àwa yóò jáde fúnra wá, ìyà pọ̀ - Oluwọde Yoruba Nation
- Ṣé lóòtọ́ ni Sunday Igboho dé síbi ìwọ́dé Yoruba Nation l‘Eko?
- "DSS tó kọlu ilé Sunday Igboho dàbí pé wọ́n gbé ‘Map’ ilé náà lọ́wọ́ ni"
- Ìlérí ta ni yóò ṣẹ láàrin àwọ̀n olùwọ̀de Yoruba Nation àti ọlọ́pàá?

