David Oyedepo, Buhari 2015 election: Mo wà lára àwọn díẹ tí Olorun fi ìràn ohun tó ń sẹlẹ hàn sáájú àsìkò yìí

Oríṣun àwòrán, Others
Bisoobu David Oyedepo to n dari ijọ Living Faith Church ti ọpọ mọ si Winners Chapel lo tun ti sọrọsoke lori ijọba Aare Buhari.
O ni ou ti kilọ iran yii ti pẹ nitori Olorun ti fi han oun lati ibẹrẹ.
O ni o hande pe ijoba Buhari kii se eyi to wa fun ohun to dara.
- Sé lóòtọ́ ni wọ́n ti fi Sunday Igboho sílẹ̀ ní Cotonou?
- Sunday Igboho àti aya rẹ́, Ropo ni ọlọ́pàá Interpol mu ní Cotonou - Agbẹjọ́rò
- Kìí ṣe tuntun pẹ ìjọba Buhari tí mú Sunday Igboho, àmọ́ ọ̀nà àbáyọ sí ìtúsílẹ̀ rẹ̀ rèé - Agbẹnusọ Sunday Igboho
- Buhari, tú Sunday Igboho sílẹ̀ bo ṣe tú Boko Haram tó ronúpíwàda sílẹ̀ - Ladoja
Lasiko ti Bisoobu Oyedepo n waasu ni Olu ijọ rẹ Faith Terbanacle to wa ni ilu Ota nipinlẹ Ogun ni guusu Naijiria.
O ni mo ti kilọ pe inu wahala ni awọn eeyan Naijiria n dorikọ ti wan ba dibo fun Buhari.
Oyedepo ni ti Wolii ba n sọrọ, O ye ki awọn eeyan maa gbọran si Wolii lẹnu.
- Wo ìgbà márùn-ún tí wọn saáyan láti mú Sunday Igboho
- Èémọ̀! Pásítọ̀ dèrò ọ̀run níbi tó tí ń l'àjà láàrin ọkọ àti ìyàwó- Iléeṣẹ ọlọ́pàá
- Ìjọba Naijiria fi pampẹ̀ òfin mú Sunday Igboho ní Cotonou
- "Buhari, kí ló dé tó ń mu Sunday Igboho àti Kanu, amọ́ tó ò mu àwọn agbébọn?"
- Adájọ́ kò yọjú lọ́jọ́ ọdún Iléyá fún ìgbẹ́jọ́ àwọn afurasí tí DSS kó nílé Sunday Igboho
- Ẹ rántí Buhari àtàwọn gómìnà nínú àdúrà bí ẹ ti ń ṣọdún Iléyá - Tinubu
O ni nigba naa ti mo sorọ naa ni awọn eeyan kan binu ti wọn ni ko dara to sugbọn bayii, oju koowa ti ja a.
Oyedepo ni oun ti ri ibanuje ati aburu yii tipẹ saaju idibo to gbe Buhari wole sipo Aarl Naijiria.












