The First Temptation of Christ: Netflix wọ̀jọ̀gbọ̀n lórí fíìmù tó ní Jesu ní ìbálòdò akọ s'ákọ

Oríṣun àwòrán, Netflix
Ariwo pe ki awọn eeyan yago fun ileeṣẹ Netflix lo gbode kan bayi loju opo Twitter, lataari sinima kan to ṣapejuwe pe Jesu ni ibalopọ akọ si akọ.
Iroyin ni awọn onibara ileeṣẹ ọhun to le ni miliọnu kan lo ti n kọwọ bọwe pe ki ileeṣẹ ọhun dawọ fiimu naa duro.
Ti wọn si n fi aidunu wọn han lori sinima agbelewo naa pẹlu ami #BoycottNetflix.
Wọn ni sinima ọhun lodi si igbagbọ awọn ọmọ lẹyin Kristi lori igbeaye Jesu.
Ki lo wa ninu sinima naa?
Sinima apanilẹrin ọhun jẹ nipa itan igbesiaye Jesu lẹyin to lo ogoji ọsan ati ogoji oru ni aginju.
Gẹgẹ bi sinima naaa ṣe gbee jade, lẹyin naa ni Jesu pada wale pẹlu ọrẹ rẹ okunrin ti orukọ rẹ n jẹ Orlando.
Fiimu naa ṣapejuwe pe Jesu ati ọrẹ rẹ Orlando yii n ni ibalopọ okunrin si okunrin, ṣugbọn Jesu sẹ.
Lẹyin naa ni Josẹfu, Maria ati Ọlọrun sọ fun Jesu pe oun ni ọmọ Ọlọrun, ti Jesu si dahun pe rara, pe iṣẹ alawada ni oun yan laayo.
Lẹyin o rẹyin ni orẹ rẹ Orlando yii fara rẹ han gẹgẹ bii Lucifa to wa dan Jesu wo.
Ẹ wo iha ti awọn eeyan kọ sinima ọhun.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1

End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4