Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ọrọ o maa tii tan lori ida aadọta afikun owo tariifu ipe ati data
Ki lo tun ṣẹlẹ o, ṣo ti walẹ ni?
Rara o! Ẹgbẹ oṣiṣẹ NLC lo kede pe awọn ṣetan lati ṣewọde tako àfikún owo ipe ati data
T'ijọba ko ba paṣẹ idaduro afikun owo naa
Lọjọ wo wa ni iwọde naa yo waye?
Alaye wa lori BBC.Com/Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Irọ nla lẹgbẹ APC n pa, Rauf Aregbesola, lo kuro ninu ẹgbẹ funra rẹ
Alukoro ẹgbẹ Omoluabi nipinlẹ Osun, Abosede Oluwaseun ti fidi rẹ mulẹ pe
ahesọ ọrọ lẹgbẹ oṣelu APC sọ pe awọn lo le gomina ipinlẹ Osun tẹlẹ kuro ninu ẹgbẹ naa
ẹgbẹ oṣelu wo ni Aregbe wa fẹ darapọ bayii?
Kan soju opo BBC.Com/Yoruba fun esi ibeere rẹ
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Awọn oṣiṣẹ adoola ẹmi ti sọ pe o ṣee ṣe ki gbogbo ero
Inu ọkọ baalu meji to fori sọra wọn ni Washington lalẹ Ọjọru ba iṣẹlẹ naa lọ
ikọ adoola ẹmi ti sawari oku eeyan mọkandinlogun to ja latinu baalu naa sinu odo
Fun ẹkunrẹrẹ iroyin yii
















