Wasiu Ayinde K1 kò lẹ́tọ̀ọ́ sí àpèrè Awujale lọ́tẹ̀ yìí, Àwọn afọbajẹ ilẹ̀ Ijebu ṣàlàyé ìlànà tí wọ́n máa fi yan Awujale tuntun
Wasiu Ayinde K1 kò lẹ́tọ̀ọ́ sí àpèrè Awujale lọ́tẹ̀ yìí, Àwọn afọbajẹ ilẹ̀ Ijebu ṣàlàyé ìlànà tí wọ́n máa fi yan Awujale tuntun
Ọrọ yiyan Awujalẹ runtun fun ipo ọba ilẹ Ijẹbu ti fa ọpọ ariwisi ati ariwo pẹlu awọn eekan to ti fifẹ han si apere nla naa.
Awuyewuye yii gan ti fa wiwọgile ilana yiyan ọmọ oye ti wọn kọkọ bẹrẹ, amọṣa awọn afọbajẹ ilẹ Ijẹbu ba BBCNews Yourba sọrọ lori ilana ti iṣẹṣe la kalẹ, ati bi awọn ṣe fẹ tọọ lọtẹ yii.