Omi Arinta, omi ńlá tó máa ń yọ̀ nígbàkúgbà tó bá rí ènìyàn ní àyíká rẹ̀
Omi Arinta, omi ńlá tó máa ń yọ̀ nígbàkúgbà tó bá rí ènìyàn ní àyíká rẹ̀
Lara awọn ibudo igbafẹ ni ipinlẹ Ekiti ni omi to n ti inu apata ṣan wa silẹ ni Arinta, eyi ti wọn n pe ni 'Arinta Waterfalls'.
BBC News Yoruba rinrinajo de ibudo igbafẹ naa nibi ti wọn ti mu awọn fidio ati aworan to jọju yii wa.
Gẹgẹbi alaye Ọba Ezekiel Ọladele, Olupole ti ilu Ipole Ilọrọ Ekiti ti omi naa tẹdo si, nnkan abami kan nipa omi yii ni pe ni kete to ba ti ri eeyan ni agbegbe rẹ ni 'yoo maa yọ' ti 'ọwọja ṣiṣan rẹ yoo tun pọ si'.
Wo fidio yii lati mọ itan to rọ mọ ilu Ipole Ilọrọ ati omi Arinta.





