"Iṣẹ́ tóo yàn láàyò lè ṣàkóbá fún ìlera ọpọlọ rẹ lọ́jọ́ alẹ́"

Àkọlé fídíò, 'Iṣẹ́ tóo yàn láàyò lè ṣàkóbá fún ìlera ọpọlọ rẹ lọ́jọ́ alẹ́
"Iṣẹ́ tóo yàn láàyò lè ṣàkóbá fún ìlera ọpọlọ rẹ lọ́jọ́ alẹ́"

Njẹ o mọ pe iru iṣẹ ti o yan laayo le ṣe akoba fun ilera ara rẹ lọjọ alẹ?

Iṣẹ iwadi ijinlẹ nipa ilera ara kan eleyii ti ajọ kan gbe jade lo ṣẹṣẹ fi idi eyi mulẹ.

Iwadii naa sọ pe irufẹ iṣẹ ti eeyan ba yan laayo nigba ọdọ rẹ le ran ilera ọpọlọ rẹ lọwọ tabi ṣe akoba fun un toba di ọjọ ogbo.

Wọn ni awọn to ba yan iṣẹ to mu arojinlẹ ati arogun dani nigba ewe , o ṣeeṣe fun wọn nigba ti wọn ba dogbo lati ni ọpọlọ to ji pepe ju awọn ti ko yan irufẹ iṣẹ bẹẹlaayo lọ.

Ẹkunrẹ alaye wa ninu fidio yii.