Akomolede ati Asa: Alagba Ajibola láti Fakunle ní olùkọ́ wa lórí ètò ìró lónìí

Àkọlé fídíò, Akomolede ati Asa: Alagba Ajibola láti Fakunle ní olùkọ́ wa lórí ètò ìró lónìí

Alagba Ajibola ṣalaye ni ọrikiniwin ohun ti iparojẹ ati isunki jẹ.

Ile ẹkọ Fakunle Comprehensive Grammar School ni Osogbo ni ipinlẹ Osun.

Iparoje ati Isunki ni Alagba Ajibola lolukọ to dantọ to n kọ wa nipa eto iro ati giram yii.

Iro konsonanti, iro fawẹli ati iro ohun ni ọpakutẹlẹ iparojẹ ati isunki.

Bawo ni iparojẹ ati isunki ṣe n waye ninu sisọ ati kikọ Yoruba?

Akomolede

Kinni Isunki?

Ona wo ni isunki n gba waye?

Wo bi iparojẹ ṣe n jẹyọ

Bawo ni awọn ọrọ wọnyii ṣe yipada?

Layelaye- laelae

Akomolede

Kekere- kekee

Olorun- Oloun

Oju ibọ- ojubọ

Iya Alaje- Iyalaje

Idi ọkọ- Idikọ?

Akomolede