Akomolede ati Asa Yoruba: Kí ni "Future tense" lédè Yorùbá?

Àkọlé fídíò, Kí ni "Present tense" lédè Yorùbá?

"Asiko ati Iba Iṣẹlẹ" ni akori Akomolede ati Aṣa tọsẹ yii.

Isọri meji ni Asiko ni ninu ede Yoruba.

Olukọ wa toni, J.A Okunlola lati ileewe girama Community High School Asewele Korede, ni agbegbe Odigbo ilu Ore, ipinlẹ Ondo ṣe atupalẹ lẹkunrẹrẹ bo ṣe yẹ ki a maa lo awọn ọrọ asiko ninu ede Yoruba.

Olukọ J. A Okunlola

"Asiko ọjọ́ iwaju" ni awọn atọka ati wurẹn ti a le fi da wọn mọ ṣugbọn ni ti "asiko afanamoni eyi ti ẹ mọ si "Past tense".

Bi awọn ẹka ede gẹẹsi sisọ ṣe mọ yin lẹnu to n yọ jade fẹẹẹ, to n dan mọran mọran lẹnu yin bẹẹ naa lo ṣe yẹ ki ede Yoruba sisọ maa fo jade lẹnu yin lai kọsẹ.