Anti social media bill: Ilé aṣòfin ní ìjíròrò ìtagbangba ló kù lórí àbá láti mójútó ayélujára

Oríṣun àwòrán, Facebook/Elisha Ishaku Abbo
Iduro ko si, ibẹrẹ ko si fun ẹni to gbodo mi lọrọ aba to wa niwaju ile aṣofin lati ma mojuto ohun to n lọ lori ayelujara lọrọ da bayii o.
Ile igbimọ aṣofin l'Abuja ti sọ pe oun yoo tẹsiwaju ijiroro lori aba naa lọsẹ to n bọ.
Igbimọ to n ri si ọrọ idajọ ati ẹtọ ọmọniyan yoo kede ọjọ kan laarin ọsẹ to n bọ fun ijiroro itagbangba lori aba ọhun.
Ọjọ Iṣẹgun ni aba naa de ipele keji nile eleyi to mu ki ọpọ tako o lori ayelujara.
Ẹgbẹ awọn agbẹjọro ni Naijiria atawọn ajafẹtọ miiran lawọn ṣetan lati da si ọrọ naa nibi ijiroro itagbangba ti yoo waye lọsẹ to n bọ.
Ohun ti ile aṣofin sọ ni pe aba yii ni yoo dena iroyin ofege lori ayelujara atawọn nnkan mii to lodi sofin tawọn eeyan n ṣe lori ayelujara.
Sẹnẹtọ Sani Musa to ṣoju ẹkun ila oorun nipinlẹ Niger lo ṣagbatẹru aba ọhun.
- Lisabi Agbongbo Akala rèé, ẹni tó fi ìfẹ́, ìṣọ̀kan àti ìrẹ́pọ̀ gba ilẹ̀ Ẹ̀gbá lọ́wọ́ ìmúnisìn
- A jọ ṣe ìyàwó pọ̀, a jọ bímọ ní ọjọ́ kan náà, a tún jọ máa ń ṣàìsàn pọ̀ ni
- Wo ìlú tí wọ́n tí ń ta ọmọ ọ̀dọ̀ kan fún #1.3M lórí ayélujára
- Andrew Haruna: So-bàtà tó di ọ̀jọ̀gbọ́n fásitì tó tún jẹ́ ọ̀gá àgbà pátá (V.C.)
Ẹwẹ, alaga igbimọ ile aṣofin to n ri si ọrọ idajọ ati ẹtọ ọmọniyan, Opeyemi Bamidele ṣalaye pe igbimọ yii yoo kọkọ ṣepade pẹlu Sẹnẹtọ to ṣagbatẹru aba naa kawọn eeyan to lanfaani lati da si i ninu ijiroro itagbangba ọsẹ to n bọ.
Sẹnẹtọ Chimaroke Nnamani to jẹ gomina ipinlẹ Enugu tẹlẹ ri nikan lo tako kile sọ aba naa di ofin.
Ẹgbẹ awọn ọdọ ati ọmọ Yoruba ati Igbo bii Ohanaeze pẹlu ẹgbẹ awọn ọdọ naa ti kilọ fun ile aṣofin pe ko jawọ lori aba ọhun.
Bakan naa ni ọgọọrọ eeyan tako aba naa lori ayelujara, niṣe lori ayelujara n gbona girigiri lati ọjọ Ẹti lori ọrọ naa.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1

End of X post, 2

End of X post, 3

End of X post, 4

End of X post, 5

End of X post, 6

End of X post, 7