Anatomy Book: Ọjọgbọn nílé ìwòsàn UCH àti UI gbé ìwé orúkọ ẹ̀yà ara lédè Yorùbá jáde

Awọn ẹya ara ọkunrin niwaju ati feremu ara
Àkọlé àwòrán, Awọn orukọ ẹya ara ọkunrin niwaju ati feremu ara lede Yoruba yii kamọmọ
Iwe ti ile iwosan UCH gbe jade
Àkọlé àwòrán, Ojogbon Durotoye Adeleke salaye ni kikun nipa iwe eya ara yii ni eyi ti egbe Atunbi Yoruba ati Oasis Health Foundation se agbateru re ni UCH ni fasiti Ibadan.
Iwe ti ile iwosan UCH gbe jade
Àkọlé àwòrán, Bi wọn se kọ orukọ ẹya ara ni ede Yoruba fun eniyan naa ni wọn kọ fun awọn ẹranko, a jẹ pe ise eniyan nise ẹranko
Awọn ẹya ara ọkunrin niwaju ati feremu ara
Àkọlé àwòrán, Bi inu eniiyan se ni itumọ orukọ lede Yoruba naa ni ita ni
Awọn eeyan to peju sibi ifilọlẹ iwe naa
Àkọlé àwòrán, Igbagbọ wọn ni wi pe ko tọ ki a maa fi ede gẹẹsi kọ ogidi ọmọ Yoruba ni eto ẹkọ, paapaa julọ awọn to n kẹkọ lẹka imọ iṣegun oyinbo
Awọn ẹya ara ewurẹ lede Yoruba
Àkọlé àwòrán, Ise eniyan nise ẹranko, ẹya ara ẹranko naa tun ni orukọ
Awọn ọjọgbọn marun ọtọọtọ ni fasiti ilẹ Ibadan lo ṣe akojọpọ iwe atumọ ede naa
Àkọlé àwòrán, Awọn ọjọgbọn marun un ọtọọtọ ni fasiti ilẹ Ibadan lo ṣe akojọpọ iwe atumọ ede naa ki ede Yoruba le tẹsiwaju
Awọn ẹya ara ọkunrin niwaju ati feremu ara pẹlu ti ẹranko
Àkọlé àwòrán, O to ọjọ mẹta ti wọn ti n gbero akanṣe iṣẹ naa ki o to di ohun ti wọn n ko jade bi ọmọ tuntun.
Awọn ẹya ara ọkunrin niwaju ati feremu ara
Àkọlé àwòrán, Iwe naa da lorii orukọ ti gbogbo ẹya ara kọọkan ti eeyan ati ẹranko n jẹ lede Yoruba pọnbele
Awọn eeyan to peju sibi ifilọlẹ iwe naa
Àkọlé àwòrán, Afojusun awọn ọjọgbọn naa ni lati tẹsiwaju ninu itumọ ede fun igbayegbadun gbogbo akẹkọ
Awọn eeyan to peju sibi ifilọlẹ iwe naa
Àkọlé àwòrán, Igbagbọ awọn ọjọgbọn ni wi pe ko tọ ki a maa fi ede gẹẹsi kọ ogidi ọmọ Yoruba ni eto ẹkọ, paapaa julọ awọn to n kẹkọ lẹka imọ iṣegun oyinbo
anatomi yoruba
Àkọlé àwòrán, Opolopo ogidi omo Yoruba lo ti n fi idunnu won han lori iwe tuntun to jade lati odo awon agba ti ko fe je ki ede Yoruba parun.
Iwe ti ile iwosan UCH gbe jade
Àkọlé àwòrán, Iwe yii lo ti jade fun lilo bayii, ki gbogbo omo Oodua lo ra ki a le tun ni imo kun imo nipa eya ara eniyan ati ti eranko ni ede abinibi wa gege bi awon ojogbon onimo kikun ninu ilera eda ati ede Yoruba ni fasiti Ibadan se gbee jade loni