Ojogbon Banji Akitoye: A ti kọ lẹ́tà sí ìjọba pé à ń ló kúrò ní Nàìjíríà, gbèndéké àsìkò ní à n dúrò dé kí a tó gbé ìgbésẹ̀ tó kàn
Adari Ilana Omo Oodua ti salaye ibi ti ọrọ ominira iran Yoruba de duro lasiko yii fun BBC Yoruba.
Ojogbon Banji Akitoye to jẹ adari ẹgbẹ́ to n ja fun ominira iran Yoruba kuro ni Naijiria gbalejo BBC Yoruba ni Republic of Benin.
Baba salaye ibi ti ija ominira naa de duro nitori pe ko gba agidi rara bikose ni tubi n nubi titi ọrọ wa yoo fi ye ara wa.
- Ẹ̀yà Yorùbá kò mọ̀ sí ìwọ́de onímílíọ̀nù kan èèyàn tí IPoB ń gbèrò - Ilana Omo Oodua
- Iṣẹ́ wa rèé lábẹ́lẹ̀ láti gba ìdáǹdè Sunday Igboho ní Cotonou - YCE
- Ilé mi kọ́ ni àwọn DSS ti kó àwon ìbọ́n tí wọ́n pàtẹ- Sunday Igboho
- Àwọn ológun Nàìjíríà pẹ̀lú agbésùmọ̀mí ilẹ̀ òkèèrè ló kọlu ilé Igboho - Akintoye
- Buhari lo fi kún ìṣòro Nàìjíríà ní ìlọ́po méjì, o ba ilẹ̀ jẹ́ gidi- Ojọ̀gbọ́n Banji Akitoye
- Sunday Igboho kọ́ ló ń gbọ́ bùkàtà ẹ̀jọ́ rẹ̀, àwa àjìjàgbara ní - Banji Akitoye
- Buhari, to bá fi pánpẹ́ ọba mú Akitoye, ohun tá ṣe rèé - Ẹgbẹ́ Ajìjàgbara ṣèkìlọ̀
Kini Akitoye sọ lori lẹta ti wọn kọ si ijoba Naijiria?
Ojogbon Banji to je alakoso Ilana omo Oodua to n ja fun Yoruba Nation salaye pe wọn ti fi iwe ifitonileti ranse si Aare Buhari to n tuko Naijiria.
won ti jẹ ki ijoba mọ pe Yoruba setan lati lọ lasiko yii gẹgẹ bi o se tọna labẹ ofin iṣọkan agbaye.
Ati pe wọn ti fun ijoba Naijiria ni gbendeke asiko kan lati fi dahun ibeere iran Yoruba ninu lẹta naa.
O salaye pe iran Yoruba ko tii gba iyọnda lati da duro ṣugbọn ireti wa pe ki ọdun yii to pari ni yoo di mimuṣẹ pẹlu iranlọwọ awọn orilẹ-ede agbaye miran ti wọn n satilẹyin fun wọn.
- Ọlọ́pàá tó bá gbá fóònù yin yẹ̀wò, ọdaràn ni – Agbẹnusọ iléeṣẹ́ ọlọ́pàá -
- Àwọn ‘Rev. Sister’ mẹ́rin tí wọ́n jígbé tí gba ìtúsílẹ̀ láìsan owó ìtúsílẹ̀
- Lẹ́yìn tí ilé wò pá ẹni méjì, Ìjọba Eko kéde gbèndéke ọjọ́ méje fún àwọn olùgbé tókù níbẹ̀
- Ìjàmbá ọkọ̀ mú ẹ̀mí èèyàn mẹ́fà lọ l’Ondo, mẹ́rin dèrò ilé ìwòsàn
- Ohun tí àwọn èèyàn ń sọ rèé lẹ́yìn tí adari àwọn agbésùnmọ́mí Zamfara, Bello Turji ní òun ti ronúpìwàdà
- Owó oṣù 'Professor' ju ti 'Perm Sec' lọ nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní 1963- Emeritus Ayo Bamgbose