HPV Infection: Àpẹ́rẹ́ àìsàn tó ń fa àrùn jẹjẹrẹ pọ̀ lára àwọn obinrin tó wà ní ìlú Ibadan - Ìwádìí fìhàn

Oríṣun àwòrán, Others
Awọn onimọ ti ni aisan nipa ibalopọ, iyẹn ''human papillomavirus (HPV) infection'' to ma n fa arun jẹjẹrẹ oju ara obinrin, ori, ọrun pọ laarin awọn obinrin to n gbe ilu Ibadan.
Awọn ti wọn parapọ ṣe iwadii naa ni ileẹkọ ileewọsan College of Medicine, University of Ibadan; ileẹkọ London School of Hygiene and Tropical Medicine, ileẹkọ London and Catalan Institute of Oncology lati orilẹede Spain.
Iwadii naa fihan pe orisirisi kokoro HPV mẹrin ọtọọtọ ni wọn ri ni ara awọn eniyan, to fi mọ awọn araalu ati awọn olowo naabi.
- Adeyemi Olubunmi Crown: Láti ìgbà ti mo ti fún ọkọ mi ni ẹ̀bùn mọ́tò ni ìfẹ́ wa ti yàtọ̀
- Ìgbẹ́jọ́ tẹ̀síwájú lórí ọ̀lọ́pàá tí wọ́n yọ ní iṣẹ́ nítórí ó gboyún láì ṣe ìgbéyàwó
- Ìdí rè é. tí ọmọ tí kò bá tí pé 18 kò ṣe lè lo ''SIM Card'' mọ́ ní Naijiria...
- Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin yan ẹ̀ní tó tí bẹ̀rẹ̀ iléẹ̀kọ́ kí wọ́n tó bíi sáyé gẹ̀gẹ̀ bí ọmọ ìgbìmọ̀ Àjọ EFCC
- Bí ẹnu rẹ bá ń rùn, ọ̀nà márùn-ún tí o lè gbà láti ṣẹ́gun ẹnu rírùn àti ìṣòrò eyín
Eleyii ti o pọju ni arun oju ara (68%), atẹle rẹ ni oju ara ti ọmọ n gba jade cervix (60%), ọna ọfun (57%), ati ẹnu(16%).
Iwadii naa ni awọn ti wọn ṣe ayẹwo rẹ ni awọn ọdọ langba ti wọn ṣi n ni ibalọpọ to jẹ ẹni ọdun mejidinlogun si ọdun marundinlaadọta ni ilu Ibadan.

Oríṣun àwòrán, Others
Lẹyin ayẹwọ ojukoroju ati ni abẹ ayẹwọ sayẹnsi ni ileewosan ni wọn ti sayẹwọ ẹnu, oju ara dfun ayẹwo arun HPV ọhun.
Kini ayẹwọ fihan?
- Awọn obinrin yii ti bẹrẹ si ni ibalopọ lati ọdun mẹtadinlogun
- Awọn ẹni ti wọn n ba ni ibalopo ju wọn lọ bii nkan bi ọdun marun
- Bakan naa ni wọn n ṣe ibalopo ti wọn n pe ni ''oral sex''
- Wọn tun n fun ara wọn ni igbadun ibalopọ(mastubation) tabi fun ẹnikeji wọn.
Iwadii fihan pe bi o tilẹ jẹpe kokoro HPV ma n kuro ni ara awọn eniyan ti eroja aṣeraloore immune eniyan ba wa ni sẹpẹ, amọ awọn miran kii lọ ti o si ma n fa arun jẹjẹrẹ si ara obinrin
- Kéére o! Ojú òpó WhatsApp kò ní ṣiṣẹ́ mọ́ lórí àwọn ẹ̀rọ ìléwọ́ yìí láti Nov 1
- Obìnrin tó bá ń gbé bùkátà kò ní ọkọ kódà kó wà nílé ọkọ - Kemi Afolabi
- 'Bóo bá ní "side chic" lẹ́nu iṣẹ́ Ọba níbí, gbígba ilé lọ yá fún ọ nìyẹn!'
- Obìnrin mẹ́rin ni igi Ọdán wó pa ni Oyo kó tó tún dìde padà- Eni tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣojú ẹ
- Ilé alájà méjì dàwó nílùú Abuja, èèyàn kan kú, orí kó àwọn míì yọ
- Irú àìsàn wo ló ń bá Sunday Igboho finra ní Benin kí sì ní àwọn àgbààgbà Yorùbá n sọ sí ọ́rọ́ yi?
- Ẹ̀yin ọmọ Naijiria, ẹ ṣóra fún ''Frozen Turkey, Chicken'' àwọn ìkà ń fí ''Formalin'' sí i- NAFDAC
- Ọwọ ọlọ́pàá tẹ afurasí ajínigbé tó máa n dibọn bí dírẹ́bà láti jí àwọn arìnrìnàjò gbé









