Lockdown updates: Naira Marley gbóríyìn fún Jude Chukwuka pẹ̀lú míliọnù kan Náírà
'Lockdown' to jẹ isede lasiko ajakalẹ arun Covid 19 n bi eso rere nipa iṣẹ ati ayanmọ awọn eeyan bii Baba awon Marlians.
Jude Ogomegulem Nnabuife Okwuwadiegu Chukwuka ni baba agbalagba ti ayelujara gbe jade to n kọ orin Naira Marley lori Instagram.
Ọmọ bibi ilu eko ni ṣugbọn iran Igbo ni awọn obi rẹ ti wa.
- Wo àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó mú Naira Marley di òrìṣà àkúnlẹ̀bọ ní 2019
- Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni Naira Marley yóò ti wo ìbúra Buhari ní May 29
- 'Soapy', àwo orin tuntun Naira Marley tó ń milẹ̀ tìtì
- Agbèfọ́ba ní òun kò leè sọ bóyá Naira Marley wọ́ ike owó àbí bẹ́ẹ̀kọ́ - Agbẹjọ́rò
- Ilé ẹjọ́ gba onídúró Naira Marley pẹ̀lú mílíọ́nù méjì náírà
Iṣẹ elere itage ni Baba awọn Marlian n ṣe jẹun.
Oghbẹni Jude ni oun ti maa n kó orin awọn ọdọ to jẹ olorin tipẹtipẹ.
- Èèyàn 789 gbèkuru jẹ lọ́wọ́ ẹbọra nítorí COVID-19 ní Nàìjíríà
- Ènìyàn 653 míràn tún kún iye àwọn tó ní COVID-19 ní Nàìjíríà
- Ǹjẹ o yẹ kí èèyàn máa sùn lẹ́nu iṣẹ́?
- Afurasí tí Ọlọ́pàá ní ó pa Barakat, Grace àtàwọn míì l'Akinyele ti sọ̀rọ̀ pé...
- Ohun mẹ́fà tí ọ̀pọ̀ kò mọ̀ nípa ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Arsenal àti Machester City
Koda, Baba awọn Marlians ni oun ti ṣe orin awọn bii QDot, Vector Tha Viper, Dagrin, 9ice ati awọn mii, kii ṣe ti Naira Marley nikan.
O ni: Mo maa n fi imu gboorun iso Naira Marley nitori mo fẹran rẹ gan an.
- Èèmọ̀! Eyín akọ̀ròyìn fò yọ lásìkò tó n ka ìròyìn lọ́wọ́ lórí tẹlifísàn
- Wo àwọn olorì àgbà mẹ́rin tí Aláàfin ń wárí fún
- Ọlọ́paàá ní wọ́n ṣèèṣì yìnbọn pa ọmọ mi tó ń tọ́ ọmọ oṣù mẹ́rin lọ́wọ́ ni- Ìyá Kager
- Wo díẹ̀ lára àwọn tí yóò kópa nínú ìdíje BBNaija ọdún yìí
- Àwọn Mùsùlùmí Sudan se ìwọ́de nítorí pé ìjọba gbẹsẹ kúrò lórí òfin tó de ọtí mímu
Baba yii ni gbajugbaja olorin ni Naira Marley fun ni ẹbun owo miliọnu kan naira lati fi gbadun ara rẹ lẹyin to ri bi Baba naa ṣe karamaasiki orin oun lori instagram.
Diẹ lara orukọ to ni awọn eeyan maa n pe oun ni: Baba Marlians, Prof. Marlians, Grandpa Marlians ṣugbọn oun kọ lati jẹ Naira Marley nitori pe oun bẹru awọn ajọ EFCC to n gbogun ti iwqa ajẹbanu ni Naijiria pupọ