'Soapy', àwo orin tuntun Naira Marley tó ń milẹ̀ tìtì

Naira Marley

Oríṣun àwòrán, INSTAGRAM@NAIRAMARLEY

Àkọlé àwòrán, Naira Marley
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Afeez Fashola ti gbogbo eniyan mọ si Naira Marley ti gbe awo orin tuntun kan jade to n jọba oju opo ayelujara lọwọlọwọ.

ẹni ọdun mẹẹdọgbọn yii ti ṣe ọpọlọpọ orin to gbode kan jade lagbo orin ni Naijiria bii 'Issa Goal' ati eyi to ṣẹṣẹ gbe jade yii 'Soapy'.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé fídíò, Kayefi BBC Yorùba: Bàbá ọmọ, Mọ́ṣúárì, Ọlọ́pàá kẹ́jọ́ rò nípa òkú ọmọ tó pòórá

Ninu fọnrán fídíò náà ti Marley fi sita loju opo Instagram rẹ, o jo iru ijo kan ti o mu ọwọ lọ si apa ibi nkan ọmọ kunrin rẹ eyi to fi n ṣapejuwe ọrọ inu orin rẹ.

Ọsẹ diẹ sẹyin ni wọn tu Marley silẹ lẹwọn nibi to wa fun ọjọ diẹ latari ẹsun ole ori ẹrọ ayelujara ti EFCC fi kan an eyi ti wọn n pe ni Yahoo Boy lorilẹede Naijiria.

Marley ni oun o jẹbi gbogbo ẹsun ti wọn fi kan an.

Ẹwẹ lati igba ti orin tuntun yii, Soapy ti jade lawọn ọmọ Naijiria ko ti sinmi ẹnu lori ẹrọ ayelujara.

Bi awọn kan ṣe n gba tiẹ ti wọn n gbe lẹyin rẹ lawọn kan n ni kii ṣe m to ṣee fi yangan.

"Emi o tilẹ ni wo fọnran orin naa rara. NAiraMarley ki lohun to n ti ẹ gbọngbọn gan?"

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

"Naira Marley yii ko lọpọlọ rara, ẹni to n kọrin lodi si aidaa ijọba, lori iṣoro awọn eeyan, aidaa awnọ ọlọpaa, laasigbo, o tilẹ n ṣe bii pe o ni iru ẹmi orin Bob Marley diẹ ṣugbọn Soapy lo n kọ. Ko lawọn eeyan gidi to yi i ka."

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

"Nigbẹyin gbẹyin mo ti ri orin ti mo le foju jọ, Soapy ti Naira Marley."

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3