Wo àwọn àdúgbò tí ìpínlẹ̀ Eko ti fòfin de ọ̀kadà àti Marwa

Oríṣun àwòrán, @others
Ijọba ipinlẹ Eko ti fofin de awọn ọkada ati marwa pe ki wọn yee rin ni awọn agbegbe kọọkan titi awọn a fi fẹnuko lori igbesẹ to ku.
Eyi yoo din awọn ọna ti ọkada n gba rin ku kaakiri ipinlẹ Eko.
Ọpọlọpọ igba lo jẹ pe ọkada ati marwa ni awọn oṣiṣẹ, ontaja ati ẹni toju ba n kan maa n saaba fi ọkada ati marwa rirnirnajo wọn nitori sunkẹrẹ-fakẹrẹ Eko.
O le ni miliọnu mọkanlelogun awọn eniyan to n gbe ni ipinlẹ Eko.
Wo awọn ibi ti ọkada ati ko ni le de mọ bayii ni ipinlẹ Eko
Awọn opopona Marosẹ:1. Opopona Marosẹ Eko si Ibadan Lagos Ibadan Expressway2. Opopona Marosẹ Apapa Oshodi Expressway3. Opopona Marosẹ Oworoshoki Oshodi Expressway4. Opopona Marosẹ Lagos Ikorodu Expressway5. Opopona Marosẹ Lagos Abeokuta Expressway
6. Babangida Bouleverde7. Opopona Marosẹ Eti-Osa Lekki Epe Expressway8. Opopona Marosẹ Lagos Badagry Express9. Funsho Williams Avenue10. Agege motor Road11. Eti-Osa Lekki Coastal Road
Wo awọn afara ti okada ati marwa ko nile rin nibẹ mọ1. Iyana-Ipaja Bridge, Ijọba ibilẹ Agege / Alimosho
2. Dopemu Bridge, Ijọba ibilẹ Agege / Alimosho3. Airport/Ikeja Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja 4. Agege Motor Road / Oshodi Loop, Oshodi, Ijọba ibilẹ Ikeja / Mushin 5. Mushin / Isolo Link Bridge, Ijọba ibilẹ Mushin Oshodi

Oríṣun àwòrán, Getty Images
6. Dorman Long Bridge Ijọba ibilẹ Surulere / Lagos Mainland 7. Ojuelegba Bridge, Ijọba ibilẹ Surulere / Lagos Mainland 8. National Stadium Flyover, Ijọba ibilẹ Surulere
9. Iganmu / Funsho Williams Bridge Ijọba ibilẹ Surulere
10. Apapa - Iganmu Bridge Ijọba ibilẹ Surulere
11. Apapa - Ijora Link Bridge, Ijọba ibilẹ Apapa/Lagos Mainland
12. Liverpool Bridge, Apapa, Ijọba ibilẹ Apapa 13. Mile 2 Bridge Loop, Amuwo-Odofin, Ijọba ibilẹ Amuwo-Odofin 14. Okota (Cele)/Ijesha Link Bridge Ijọba ibilẹ Mushin / Oshodi-Isolo 15. Apakun/Apapa-Oshodi Bridge Network, Ijọba ibilẹ Mushin / Oshodi / Isolo
Àǹfààní wo ló wà nínú Brexit fún Nàìjíríà àtàwọn orílẹ́-èdè Afíríkà?16. Ikorodu Road / Anthony Clover leaf Bridge Ijọba ibilẹ Somolu / Ikeja 17. Trade Fair Flyover Bridge, Ijọba ibilẹ Ojo 18. Festac / Amuwo-Odofin Link Bridge Ijọba ibilẹ Amuwo Odofin 19. 2 Flyover bridges along Alhaji Masha Rd, Ijọba ibilẹ Surulere20. Ojota Clover Leaf Bridge, Ijọba ibilẹ Kosofe / Ikeja
21. Ogudu Bridge Ijọba ibilẹ Kosofe
22. 3rd Mainland Bridge, Ijọba ibilẹ Lagos Island / Mainland / Somolu 23. Maryland flyover Ijọba ibilẹ Ikeja / Somolu
24. Ikeja / General Hospital flyover Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja 25. Kodesho Bridge, Oba Akran, Ikeja, Ijọba ibilẹ Ikeja
26. Opebi Link Bridge, Ikeja Ijọba ibilẹ Ikeja 27. Sheraton-Opebi Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja Ikeja 28. Jibowu/Yaba flyover Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Mainland 29. Carter Bridge Lagos, Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Mainland 30. Bariga-Ifako Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe31. Apapa -OShodi Expressway / Alapere Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe32. Bariga / Oworonshoki Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe

Oríṣun àwòrán, Getty Images
33. Apapa - Oshodi Expressway / 3rd Mainland Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe 34. Apapa - Oshodi Expressway / 3rd mainland Bridge, Ijọba ibilẹ Ikeja Somolu / Kosofe 35. 3rd mainland / Oworonshoki Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Kosofe 36. Eko Bridge Lagos Island / Lagos Mainland 37. Apongbon flyover, Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Island 38. Cowry Bridge (Officers Mess) Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Island / Eti-Osa.39. McWen Bridge (Bonny camp) Ijọba ibilẹ Ikeja Eti-Osa.40. Marina / Ikoyi Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Lagos Island / Eti-Osa41. Ikoyi / Obalende Bridge Ijọba ibilẹ Ikeja Eti-Osa.
Afurasi onisowo ibọn wọ gau agbofinroAwọn ọna miran:Ni ijọba ibilẹ Agege1. Oba Ogunji Road2. Old Abeokuta Road3. Capital Road4. Alfa Nla Road5. Oko-Oba Road6. Akilo Street7. Agunbiade Road8. Ogba Road9. Ipaja Road10. Maricas Road
11. Oyewole Road12. Arigbanla Street13. Dopemu Road14. Oke-koto Road15. Oniwaya Road16. Adebisi Awosoga Street17. Old Ota Road18. Ijaiye Road19. Akin Doherty Road20. Amoo Street21. Pen Cinema Round About22. Surulere Street23. Agbedeji Street24. Ayige Street25. Sule Street26. Ashipa Street27. Salawu Street
















