Tunde Bakare: Àjọjẹ kò dún bẹ́nìkan kò ní ló fa ìjà Sunday Igboho, bẹ́ẹ̀, Orí àwọn Ọ̀dọ́ tó gbàjọba lọ́pọ̀ ọdún sẹ́yìn tó tún kọ̀ láti fipò sílẹ̀ lárúgbó ní Nàìjírìà ti bàjẹ́
Bata to n ro lakọlakọ to fẹ ya ni ọ̀rs ìjọba Buhari- Tunde Bakare.
Bata to n ro lakọlakọ to fẹ ya ni ọ̀rọ̀ ìjọba Buhari- Tunde Bakare
Ọ̀jẹ̀lú ló bá wa dé ibi ni Naijiria ti kii ṣe iṣelu rara- Pasito Tunde Bakare.
O ni: Awọn oloṣelu Naijiria ti gbe pẹpẹ lọ kii ṣe pe wọn n jẹ ni idii pẹpẹ nikan.
- Ẹ̀yin òṣìṣẹ́ ìjọba, ìyà yóò jẹ orí yín bí Nàìjíríà bá pínyà pẹ́rẹ́, toríi Yoruba Nation! - Oluwo
- Nǹkan kò burú tó báyìí ní ọgbọ̀n ọdún sẹ́yìn tí mo kọrin pé kí Ọlọ́run bá wa tún Nàijíríà ṣe- Funmi Aragbaye
- Àwọn ọ̀dọ́ lé kábíyèsí jáde láàfin l'Ondo
- A ti rí ọmọ ilé kéú 11 míì nínú àwón tí agbébọn jí gbé ní ìpínlẹ̀ Niger
- 'Mo fẹràn Daddy mi ju Mummy lọ torí wọ́n fẹ́ mú mi lọ sí Canada'
- 'Kò sí ààtò fún òfin Sharia àti ẹtọ àwa ẹlẹsìn Islam nínú Oduduwa Republic, a ò gbà!'
Tunde Bakare to jẹ ogbontarigi ojiṣẹ Olorun to n dari ijọ Citadel Global Community Church gba BBC Yoruba lalejo.
O salaye kikun nipa iṣelu Naijiria lati ọdun 1999.

Bakare ni: Mi o ranti boya a ni kọkọrọ ti a fi n tilẹkun nile baba mi.
O mẹnuba ipileṣẹ nibi ti ẹru Naijiria ti wọ wa.
O ni: Bi ologun ko ba ba ilu jẹ, wọn kii kuro nibẹ, wọn maa n ṣọ ara wọn di 'Ecomog' ni.
- Wo bí o ṣe lè dá bàtà gidi mọ́ kí o tó rà á
- 'Mo fẹràn Daddy mi ju Mummy lọ torí wọ́n fẹ́ mú mi lọ sí Canada'
- Ọwọ́ ikọ̀ Amọtẹkun ba Mutiu Abdul-Rasheed, afurasí tó ń ta ẹ̀yà ara èèyàn ní Ibadan
- Ilẹ̀ Yorùbá kìí ṣe ibi kátàkárà fún yín, ẹ̀yin àgbà tẹ ń gbárùkù ti ọ̀dọ́ lẹ́yìn láti máa da ìlú rú ẹ sọ́ra - Ẹgbẹ́ YWG
Nibi ifọrọwerọ pẹlu BBC Yoruba, Pasitọ Tunde Bakare ni iyan Naijiria ti di atungun nitori pe ibeere to yẹ ka maa beere ni pe lati ọdun 1999 n kọ?
Se ko tii yẹ ki iyipada wa laye olugbe Naijiria ni?
Pasito Tunde Bakare ṣalye fun BBC pe iran ni oun ri ki oun to bẹrẹ iṣelu ati ayipada ni Naijiria lo jẹ oun logun.

Lori ọrọ Buhari:
Bakan naa lo mẹnuba irinajo rẹ pẹlu aarẹ Buhari, bi wọn ṣe pade ati ọrọ oselu awon mejeeji.
O ni titi di isinyi ni oun n ba Buhari sọrọ ṣugbọn o kan maa n gbọ ni, kii gba a wọle.
Bakare ni kaka ko san lara ọmọ iya Ajẹ Buhari ni, niṣe nijọba rẹ n fi gbogbo ọmọ bi obinrin ti gbogbo nkan n dojuru
Bakare ni ọpọ ọrẹ oun lo n fi Buhari bu oun.
O ni Adura lo ku lori ọrọ Naijiria ati pe oun ko ni salọ sibi kankan nitori o ṣi maa dun.
Bakare ni koda, oun ati awọn ọmọ oun maa n tọwọ bọwe ni lori pe wọn gbọdọ pada wa si Naijira lẹyin ẹkọ wọn loke okun.
- Òṣìsẹ̀ 170 tí Ajimobi lé ni Lautech ni ń o gbà padà, owó osù márun wọ́n yoo di sísan- Gómínà Oyo
- Ohun tí wọ́n ní kí òkóbó Buhari bọ̀ lórí ọ̀rọ̀ àbò ni kó bọ̀, dípò dídúnmọ̀huru mọ́ aráàlú- PDP
- Ilẹ̀ Yorùbá kìí ṣe ibi kátàkárà fún yín, ẹ̀yin àgbà tẹ ń gbárùkù ti ọ̀dọ́ lẹ́yìn láti máa da ìlú rú ẹ sọ́ra - Ẹgbẹ́ YWG
- Èrò Akeredolu ni yẹ́n, àwa aṣòfin á ṣẹ̀sẹ̀ jókòó láti yọ tàǹda kúrò nínú ìrẹsí nígba tó bá ya- Senetọ Ajibola
Lori ọrọ Sunday Igboho:
Tunde Bakare sọrọ lori ọrọ Sunday Igboho pe nitori nkan fi sibi kan ju ibi kan lọ ni awọn ọdọ Yoruba ṣe n gbarata.
O ni ti o ba kari, ko sẹni to maa ja.
O ni ti igba ba yipada ko ni si wahala ni ẹkun kankan mọ




