Àwọn ọ̀nà láti fi dá ìròyìn òfégè mọ̀ lásìkò ìbò 2023 nìyí
Ni Oͅjoͅ Karundinloͅgboͅn, Osͅu Keji, oͅdun 2023 yii ni awoͅn omoͅ Naijiria yoo jade lati dibo yan eͅni ti woͅn feͅ ko jeͅ adari tuntun lorileͅede Naijiria.
Ni igbaradi fun idibo naa ni awoͅn eniyan n loͅ si ori eͅroͅ ayelujara lati moͅ bi o sͅe n loͅ ninu eto idibo to n boͅ naa.
Amoͅ oju opo ayelujara ko ṣe e gbeͅkeͅle to beͅeͅ nitori oͅpoͅloͅpoͅ iroyin ofege lo ti gba ori eͅroͅ ayelujara kan.
Eyi ni akojoͅpoͅ ilaniloͅye lori oͅna lati da iroyin ofege moͅ lori eͅroͅ ayelujara lasiko eto idibo yii.
Amoͅ, kiyesi awoͅn iroyin ti o ba ri lori eͅroͅ ayelujara ki o si wo finifini ki o to pin iroyin naa.
- Ẹnikẹ́ni tí ọwọ́ bá tẹ̀ tó ń pín ẹ̀bùn tàbí tó ń gba ẹ̀bùn owó fi ra ìbò yóò ṣẹ̀wọ̀n-EFCC
- Ìwádìí BBC tú àṣírí àwọn ojú òpó kàn tó n pín ayédèrú ìròyìn kà nípa ìdìbò Nàìjíríà
- Torí N200,000 ni mo ṣe lẹ̀dí àpò pọ̀ mọ́ ajínigbé láti jí bàbá mi gbé - Afurasí
- Ọ̀pọ̀ èèyàn farapa lásìkò tí àwọn jàndùkú kọlu àwọn alátìlẹyìn Kwakwanso ní Kano
- Mọ̀ síi nípa ewu tó rọ̀ mọ́ níní ìbálòpọ̀ lásìkò ìlóyún lórí ètò Sé lóòtọ́ ní BBC
- Àwọn nǹkan tí o gbọ́dọ̀ mọ̀ kí o tó lọ sí ibùdó ìdìbò nìyí
Sayeͅwo aworan to ba joͅ ti atijoͅ finifini
Awoͅn fidio kan wa lori ayelujara to jeͅ peͅ ti idibo to ti koͅja si eͅyin ni, abi awoͅn eleyii ti woͅn sͅe lorileͅede miran,amoͅ ti awoͅn eniyan gbe jade geͅgeͅ bi ohun to waye ni Naijiria.
Ni igba miran woͅn yoo ti sͅe ayederu iroyin yii lati sͅakoba fun oludije kan tabi omiran.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Amoͅ bawo ni a sͅe le moͅ wi pe iroyin ofege ni?
Ohun akoͅkoͅ ti yoo fi iru iroyin ofege yii han ni iru aworan to wa nibeͅ.
Nigba miran awoͅn aworan ofege naa ko ni dan moͅran, bai bai ni yoo ri
Nitori naa koͅkoͅ wo boya fidio naa jeͅ tuntun abi oͅjoͅ ti loͅ lori reͅ? Lo imoͅ eͅroͅ 'reverse image' lati fi wo igba ati akoͅkoͅ ti fidio tabi aworan naa koͅkoͅ jade.
To ba jeͅ fidio, wo finifini, sͅe awoͅn ohun to wa ninu reͅ joͅra rara? Iru asͅoͅ wo ni awoͅn eniyan ibeͅ woͅ? Iru asia wo ni woͅn gbe dani, ki ni ami idanimoͅ eͅgbeͅ osͅelu naa ati awoͅn ohun miran to sͅe koko.
Bakan naa ni ki o ranti lati gboͅ ede ti woͅn n soͅ ninu fidio naa.
- Agbébọn ṣekúpa akọ̀ròyìn lẹ́nu iṣẹ́ àti ọmọdé kan ní Florida
- Ọwọ́ Ọlọ́pàá tẹ Chinyere Igwe ti ẹgbẹ́ PDP pẹ̀lú owó tó tó $498,100 ní Rivers
- Ọ̀pọ̀ èèyàn farapa lásìkò tí àwọn jàndùkú kọlu àwọn alátìlẹyìn Kwakwanso ní Kano
- Ọmọ tí wọ́n bá fi èdè Yorùbá kọ́ ní ẹ̀kọ́ máa ń pegedé jú tí èdè míràn lọ- Ọjọgbọn Ogundeji
- 'Àwọn ọ̀gá wa máa ń fipá bá wa lòpọ̀ kí wọ́n tó fún wa ní iṣẹ́'
- Wọn kò tíi bí ọkùnrin tí kìí ṣe ṣìná sáyé- Olori Sekinat Elegushi
Sayeͅwo akoͅle awoͅn iroyin ti ko ja geere
Awoͅn iroyin ofege nipa eͅgbeͅ oselu kii lo ni oͅna kan ti yoo yeͅ awoͅn eniyan. Ti woͅn ba feͅ gbe iroyin ofege nipa oludije, eͅgbeͅ oselu tabi ojuko idibo kan, iroyin naa ki n ja geere.
O seese ki o ri iroyin ofege lara awoͅn oͅreͅ reͅ to n tele oju opo woͅn lori eͅroͅ ayelujara.
Iwadii ti ileesͅeͅ iroyin BBC se safihan pe awoͅn awoͅn eͅgbeͅ oselu koͅoͅkan ma n san owo fun awoͅn to jeͅ ilumoͅoͅka influencers lori eͅroͅ ayelujara.
Nitori naa lati sͅayeͅwo iroyin boya ofege ni tabi otitoͅ, o gboͅdoͅ wo ju akoͅle iroyin naa loͅ
Wo ibi ti iroyin naa ti sͅeͅ wa? Se awoͅn to n gbe iroyin ofege ni abi beͅeͅ koͅ. Wo awoͅn ileesͅeͅ iroyin to jeͅ ilumoͅoͅka, ti woͅn ko bagbe iroyin naa, o sͅeesͅe ko jeͅ iroyin ofege ni.
Awͅn ojuko iroyin kan wa lori eͅroͅ ayelujara to jeͅ iroyin ofege nikan ni woͅn ma n gbe jade.
O seese ki woͅn gbe esi idibo ofege jade, woͅn kii ni oͅpoͅloͅpoͅ awoͅn eniyan to n teͅleͅ woͅn lori eͅroͅ ayelujara.
- Ebi ń pa wá, kò sówó ṣùgbọ́n síbẹ̀, a máa dìbò yan ẹni tó wù wá- Awọn ọmọ Nàìjíríà
- 'Àwọn ọkùnrin gan mọ̀ pé àwọn nílò àwa obìnrin nínú òṣèlú, ìdí tí èmi fi wọ òṣèlú ni pé...'
- Olùdíje sílé ìgbìmọ̀ aṣòfin pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ sọ́wọ́ àwọn agbébọn ní ìbò ku ọjọ́ kan, wọ́n tún dáná sun òkú rẹ̀
- Ọmọ tí wọ́n bá fi èdè Yorùbá kọ́ ní ẹ̀kọ́ máa ń pegedé jú tí èdè míràn lọ- Ọjọgbọn Ogundeji
- Nàìjíríà máa dára síi tí obìnrin bá pọ̀ tó bá pọ̀ síi nínú ìjọba nítorí ọpọlọ pípé wọn
- Àṣé nǹkan ìṣeré ìbálòpọ̀ oní igi ti wà lọ́jọ́ pípẹ́- Ẹ wo ìtumọ̀ ara rẹ̀ tó ń dán gbiirin yìí
Bakan naa ni woͅn kii se ojuko iroyin to ti peͅ loju opo ayelujara.
Eͅ sakiyesi ti eͅni to n se apinka iroyin naa ti ko ba ni aworan to n sͅapejuwe reͅ, o ri bakan, nitori naa eͅ kiyesara nipa iroyin to ba jade nibeͅ.
Amoͅ to bani aworan, lo 'reverse image' lati wo aworan naa, yoo soͅ ibi ti iroyin naa ti wa.
Ki o to sapinka iroyin, o dara lati koͅkoͅ bi ara reͅ ni awoͅn ibeere koͅoͅkan ki o si wo idahun reͅ fun ara reͅ
Wo eͅni to n pin iroyin naa ati pe kini idi to fi n pin iru iroyin beͅeͅ. Ti o ba jeͅ pe woͅn feͅ ki iroyin naa ru oͅkan awoͅn eniyan soke ni, yala ibinu abi ikorira, o seese ko jeͅ iroyin ofege.

