BBC Africa Eye: Àìríṣẹ́ ṣe àti gbèsè ló mú kí ẹlòmíì gba kádàrá níbi iṣẹ́ oko tí a ń ṣe iṣẹ́ ni Kenya

Àkọlé fídíò, BBC Africa Eye: Àìríṣk ṣe àti gbèsè ló mú kí ẹlòmíì gba kádàrá níbi iṣẹ́ oko tí a ń ṣe

75 ninu obinrin 100 ti a ba sọrọ ni Kenya lo fidi ọrọ yii mulé pe wọn ti fipa ba awọn lo pọ sẹyin nileeṣẹ naa.

Ikọ iwadii BBC Africa Eye tu aṣiri àwon mọ́nija ti wọn n beere fun ibalopọ ninu méjì lára iléeṣẹ Britiko to wa ni Kenya.

BBC ṣe iwadii naa pẹlu ọgọrun un kan obinrin nibi ti obinrin marunle ni aadọruin ti fidi ẹ mulẹ pe ootọ ni awon alamojuto ileeṣẹ tíì mejééji ti wọn fẹsun kan maa n fi ibalopọ lọ wọn nigba gbogbo.