Ayantola Adebayo: Iṣẹ́ abẹ ẹẹ̀méjé ni wọ́n ṣe fún mi láti kékeré ṣùgbọ́n mo padà ni ìpènijà ojú lágbà náà ni- Shanko Alhaji
Orisiirisii ipenija ni awon akanda ẹda n koju lawujọ wa.
Opọ lo si maa n yẹra fun wọn nitori ipenija ti wọn ni.

BBC Yoruba ba Pasito Shanko Alhaji, gbajugbaja sọrọsọrọ lori afẹfẹ to tun ni ipenija oju sọrọ lori ohun ti oju rẹ ri to lati kekere.
O ni pe: O lé ní ogójì obìnrin tó jámikulẹ̀ kí ń tó rí aya fẹ́- Pasito Shanko Alhaji
O ni oun pada dupe pe oun ri iru aya ti oun fẹ sile ni iyawo nigbeyin.
Ayantola Adebayo Ayanwale to tun jẹ oluko sọrọ nipa ohun ti o la kọja ki o to ri aya gbe sile.
O ni ọpọ obinrin lo fẹ fẹ oun ti won ba ti gbọ ohun rẹ lori afẹfẹ sugbon ti won a yi ohun pada ti wọn ba ti ri i pe oun ko riran.
Ni ipari, Pasito Shanko Alhaji gba awọn ọdọ ati akanda ẹda nimoran pe ki won ma ro ara wọn pin laye.
O tun gba Naijiria nimọran lati yi iwa rẹ pada si awọn to ni ipenija ara.
- Èmi kò kí ń gba 'Bribe'tàbí mú ọkọ̀ tàbí ọlakadà lẹ́nu iṣẹ́- Olaseni Gbenga Olùdarí ọkọ̀
- Wo Mẹkáníìkì alápá kan tí ayé ń pariwo pé o mọ ìjánu ọkọ̀ ṣe púpọ̀
- Báyìí kọ́ ní wọ́n ṣe bí èmí àti aya mi ṣùgbọ́n a kọ̀ láti tọrọ bárà- Tokotayà tó ni ìpènijà oju
- Èèyàn 300 ló ya bò mí pé mo gbé kẹ̀kẹ́ Márúwá - Portable Zazzu
- Wo ìdí tí Buga ṣe kọ orin: Mummy ooo, wá pẹ́ láyé...níbi



