Olaseni Gbenga 'Yellow fever, Traffick warden": Èébú kìí dùn mi tí mo bá ń jó lẹ́nu iṣẹ́
Eba ni orukọ inagije ti ọpọ n pe Olaseni Gbenga to n ṣiṣẹ adari ọkọ.
O jẹ olọpaa " Yellow Fever" ti a mọ si " Trafick Warden"
Oṣu kinni, ọdun 2007 lo darapọ mọ wọn ni Akurẹ ni ipinlẹ Ondo ni Guusu Iwọ Oorun Naijiria.
Eba maa n fi ijo da ọpọ laraya nigba to ba wa lẹnu iṣẹ rẹ.
O gbalejo BBC Yoruba ni Akure
- Pásítọ̀ ti ríran sí mi pé mà á jẹ Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ọdún 2018- Dele Momodu
- Ọta ìbọn bá Pásítọ̀ tó ń gbàdúrà lórí òkè, ikú dé lójijì
- Wo ọmọ Nàìjíríà mẹ́fà tí ayélujára sọ di ìlúmọ̀ọ́ká
- Ki gan an ló mú kí awuyewuye pọ̀ lórí ìkéde èròngbà Tinubu láti du ipò ààrẹ Nàìjíríà?
- Àlàyé rèé lórí bí àwọn agbébọn ṣe pa ṣọ́jà méjì, ọlọ́pàá àtọ̀pọ̀ olùgbé ìletò kan ní Kebbi
Gbenga Olaseni ni oun kii mu ọlọkada tabi onimọto rara nitori iṣẹ oun kọ ni yẹn bi ko ṣe lati maa dari ọkọ loju popo.
O ni eebu kii dun oun ti oun ba ti n jo
Olaseni gba awọn oṣiṣẹ bii tirẹ ni imọran pe ki wọn jọ fọwọsowọpọ fi tun Naijiria ṣe.
- Azeez ló tà wá láti Nàìjíríà fún Michael ní Libya kí a tò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ aṣẹ́wó lẹ́yìn ti mo ta ṣọ́ọ̀bù ọjà mi- Fatimah
- Irú ọmọ wo ni Yorùbá máa ń pè ní Ìgè?
- Mo mọ èsì ọ̀rọ̀ kẹ̀, Queen Salawa Abeni ló kọ́kọ́ ta sí mi pé èmi 'Alaragbo ọmọ bàbá olójú kan' ní 1980s - Kuburat Alaragbo
- Àlfàá ò bá mi jà, Babaláwo ò bá mi jà, ẹ jẹ́ kí n sọ ìdí táwọn Krìstẹ́nì ṣe ń bínú tórí ìwàásù "hell fire" - Mummy G.O
- 'Fire Boy' lo ni orin 'Wọ́n n wá mi yẹn', èmi kàn lò ó ni kó tó dí ńlá mọ́ mi lọ́wọ́- Tolibian
- Ojú máa ń tì mí láti rẹ́rìn ín nítorí irú eyín ẹnu mi ṣùgbọ́n mo dúpẹ́ mo padà dí arìnrìnoge- Omotola Ekundayo