Abubakar Ottan Abdulmutolib: 'Fire Boy' lo ni orin 'Wọ́n n wá mi yẹn', èmi kàn lò ó ni kó tó dí ńlá- Tolibian
Abubakar Ottan Abdulmutolib ti ọpọ eeyan mọ si Tolibian ni BBc gba lelejo.
O sọrọ nipa orin to gbe e jade eyi to kọ pe: Won n wa mi.
Tolibian sọ pe olorin 'Fire Boy' lo kọ orin naa ati pe oun kan kọ ẹda orin ọhun lasan ni ki Eledumare to sọ ọ di ootọ mọ ohun lọwọ.
- Lẹ́yìn wákàtí mẹ́ta tí wọ́n kéde pé ìyá mi kú, ó tún mi ọwọ́ rẹ̀ ooo - Ọmọ Iyabo Oko
- Wo kókó méje tí Aàrẹ Buhari mẹ́nubà lásìkò ìfọ̀rọ̀wérọ̀ rẹ̀
- Sanwo-Olu ṣèlérí láti ṣiṣẹ́ lórí àbọ̀ ìgbìmọ̀ olùwádìí ilé alájà 21 tó wó ní Ikoyi
- 'Ìdí mẹ́rin tí Gómìnà Abiola Ajimobi ṣe fún Lekan Balogun àtawọn tó kù ní adé'
- Erin tẹ obìnrin kan àti ọmọ rẹ̀ pa lọ́jọ́ ọdún
Abdulmutoib Ottan sọ pe ohun kan fẹran lati maa ṣawada lati kekere ni.
O ni ọmọ Ekiti ni iya oun ti baba oun si jẹ ọmọ Ilorin.
- Ká má rí! Kò sí aàyè fún ìdìbò Gómìnà ní Osun àti Ekiti- Ilana Omo Oodua
- Èsì àyẹ̀wò òkú Sylvester Oromoni kò fihàn pé ẹnikẹ́ni ló pa á - Kọmiṣọnna ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Eko
- Ìṣẹ̀ṣe, Àṣà àti àwọn ìgbésẹ̀ wọ́nyìí ní a máa fi yan Olubadan tuntun....- Ìgbìmọ̀ Ìṣèjọba Olubadan
- Mọ̀ nípa òfin tuntun tó lé mú kí èèyàn rí ìrànlọ́wọ́ ìjọ̀ba láti gbẹ̀mí ara rẹ̀
- Wọ́n ti sin òkú Alhaji Bashir Tofa ni Kano báyìí
- Koiki àti Olajengbesi ń jíṣẹ́ ara wọn ni, Igboho kọ́ ló rán wọn níṣẹ́, Agbẹjọ́rò Sunday Igboho faraya
Tolibian mẹnuba pataki awọn eeyan bii Cute Abiola, Dr Bayo, Baba ko rough ati awọn eeyan mii ninu irinajo re si awada ṣiṣe ati orin kikọ.