Disability: Àwọn òbí mi gbìyànjú títí ní kékeré mi ṣùgbọ́n ...

Àkọlé fídíò, 'Mo fọ́ lójú ṣùgbọ́n mo mọ gbogbo irinṣẹ́ tí mo fi ń ṣe mọkalíìkì'

Ẹni to nilo oju lati fi ṣe iṣẹ ọwọ rẹ ṣugbọn to ti bábá padanu oju. Bawo lo ṣe n ṣe e?

Emeka Abugu ni oun di afoju lọmọde tori aisan igbona.

Awọn obi rẹ gbiyanju titi wọn ṣa ipa wọn, wọn gbe e kaakiri fun ayẹwo ati itọju.

Nigba to dagba tan lawọn dokita sọ fun un pe oju rẹ ti fọ tan patapata ko le riran mọ

Ọdọ baba rẹ lo ti bẹrẹ si ni lo irinṣẹ bii "Spanner" lati tun kẹkẹ ṣe.

'Mo fọ́ lójú ṣùgbọ́n mò ń tún àwọn ọkọ̀ tí iṣẹ́ rẹ̀ lè ṣe.

Oju inu ni Emeka fi n ṣe gbogbo iṣẹ rẹ̀ to si fi n wo gbogbo awọn irinṣ to yẹ ko lo.

"Mo máa ń rí wọn pẹ̀lú ojú ẹ̀mí. Emi gan ni mo maa n lọ ra ẹya ara ọkọ fun'ra mi".