Food Packaging: Èmi ni mò ń sin ẹran ògúfe tí mò ń pa àti dín ráńṣẹ́ s'ókè òkun

Àkọlé fídíò, Ọbẹ̀ ni, ẹran ni o, irú oúnjẹ wo lẹ́ fẹ́, ká báa yín sè é wá sílé yín?

Adepeju Ruth jẹ alase to n lo ọwọ ṣibi lọna ara.

Bi Adepeju ṣe bẹrẹ to ń dín ẹran tó sì ń gbé é ráńṣẹ́ sí ìlú òyìnbó jẹ itan ti oun funrarẹ ko le sọ tan.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

"Àwọn oníbara ẹran díndín mi wà ní US, UK, Canada, Durblin, Dubai".

Koda Adepeju ni bi ẹyin ba fẹ ọbẹ tabi ounjẹ pupọ tẹẹ fẹ gbe sinu ẹrọ amunu tutu, ikawọ awọn lo wa.