Rasheed Tijani: Ìpèníjà ojú kìí ṣe ìdènà sí ọ̀nà àtijẹ mi

Àkọlé fídíò, Ẹni ti ko riran to nlọ'ta ni Mushin

Rasheed ni ipenija oju ṣugbọn ko jẹ k'o fa idiwọ fun oun lati ṣiṣẹ oojọ rẹ nibi ti o ti nlọ ata.

Ki enikeni ma ṣe ro ara rẹ pin nile aye, nitori bi oni ti ri ọla ko ri bẹẹ

Iru awọn iroyin ti ẹ le nifẹ si: