LASTMA Yesufa: Àwọn dókítà gbìyànjú lórí ojú mi ṣùgbọ́n...
LASTMA gbiyanju pupọ fun mi -Yesufa.
Ọrọ iyanu nla ni igbeyawo arakunrin Olawale Yesufa to jẹ oṣiṣẹ ajọ ẹṣọ oju popo nipinlẹ Eko, LASTMA.
Lẹyin igbeyawo to gba ori opo ayelujara kan ni BBC Yoruba lo wadii ijinlẹ ohun to sọ ọgbẹni yii di afọju ọsan gangan.
O mẹnuba ipa pataki ti ajọ LASTMA ko lati jẹ ki oun riran pada lẹyin iṣẹlẹ yii to ja si pabo.
- Iléẹjọ́ ní kí ìyà akẹ́kọ̀ọ́ Iléẹ̀kọ́ Deeper Life tó ní wọ́n fipá bóun lòpọ̀ yé sọ̀rọ̀ mọ́ lórí ayélujára
- Wo orílẹ̀-èdè tí ọ̀kọ̀ọ́kan àwọn aṣojú Naijiria yóò ti ṣiṣẹ́ jákèjádò àgbáyé
- Ooni Ile ife ṣàlàyé ohun tí Tinubu níló fún ilépa ipò ààrẹ lọ́dún 2023
- Kókó mẹ́rìn tí Joe Biden ṣetán láti ṣe àti bó ṣe lè kàn ọ́
- Ìgbìmọ̀ aláàṣẹ Nàìjíríà ti buwọ́lu ọjọ́ orí ìfẹ̀yìntì tuntun fún àwọn olùkọ́
Ogbẹni Yesufa Olawale ṣalaye fun BBC Yoruba bi oju rẹ ṣe deede ṣalai riran mọ laisko to wa lẹnu iṣẹ ni Oregun ni Ikeja ni ipinlẹ Eko.
O sọrọ lori bi oun ṣe pade ololufẹ oun, Yesufa Adenikẹ lẹnu ikọni nipa igbe aye afọju ati awọn ipenija rẹ gbogbo.
Oṣiṣẹ LASTMA yii yombo ajọ LASTMA ati ohun gbogbo ti wọn ṣe fun un ki inu rẹ le dun lẹnu iṣẹ oojọ rẹ.
- Ìdí rèé tí ilẹ̀ Afirika fi gbọdọ̀ kópa nínú dídán abẹ́rẹ́ coronavirus wò
- "Ẹ̀wọ̀n gbére leè jẹ́ ìjìyà fún afipábánilòpọ̀ bí àwọn gómìnà ṣe dìde si"
- Kíló fáà tí Póópù fi fẹnú ko ẹsẹ̀ àwọn olórí South Sudan?
- Orí ló mọ iṣẹ́ àṣelà
- 'Iṣẹ́ aṣẹ́wó ni iṣẹ́ tó ni mi lára jùlọ láti ṣe nínú tíátà'
- Orin mi ń gbé àṣà Áfíríkà ga lókè òkun - Kakaki 1