Ìyá àkàndá ẹ̀dá: Àwọn ẹbí mi fẹ́ kí n pa ọmọ mi torí ó jẹ́ àkàndá ẹ̀dá
Ajọ to n ja fun ẹtọ awọn akanda ẹda lagbaye (Disability Rights International) sọ wi pe, ni orilẹede Kenya, Ida mẹrindinlaadọrin iya akanda ẹda lo ni, awọn mọlẹbi ati ara ma n gbe ẹmi awọn gbọna lati pa awọn ọmọ wọn to jẹ akanda.