Sola Allyson: Ẹ̀ báà sọ pé Wákà ni tàbí Fuji tàbí orin Ara, kò ṣe ǹkankan fún èmí, pàtàkì ibẹ̀ nìyí
Ṣọla Allyson, tii se ilumọọka olorin ẹmi ti ṣalaye irufẹ ati ipa ti awọn orin rẹ n ko ni idahun si awọn ti ko ye nipa ibi ti wn lee fi isọri orin rẹ si.
Lasiko to n ba BBC Yoruba sọrọ, o ṣalaye pe, ọpọ eniyan to wọn ti pinnu lati pa ara wọn, amọ ti wọn gbọ orin oun nigba to ku diẹ ki wọn gbe igbesẹ naa, ni wọn yi ero wọn pada.
- Ìdí tí mi ò fi lègbà kí ẹnikẹ́ni fọwọ́ tẹ ara mi gẹ́gẹ́ bí olórin - Sola Allyson
- Ọ̀pọ̀ àwọn tó fẹ́ ràn mí lọ́wọ́ ló fi ìlọ̀kulọ̀ lọ̀ mí, àyàfi Dudu Heritage nìkan
- Kí ló ṣẹlẹ̀ láàrin Yinka Alaseyori àti Sola Allyson tí Alaseyori ń bẹ̀bẹ̀?
- Ìdí tí mi ò fi lègbà kí ẹnikẹ́ni fọwọ́ tẹ ara mi gẹ́gẹ́ bí olórin-Sola Allyson
- Ọlọ́run sọ fún mi nínú ẹ̀mí pé ẹnu Yorùbá kò ṣọ̀kan fún ìdásílẹ̀ Yorùbá Nation - Funmi Aragbaiye
- Wo ìdí tí Buga ṣe kọ orin: Mummy ooo, wá pẹ́ láyé...níbi
- Irọ́ ni pé àwọn ọmọ Sàtání ló ń kọ Fuji Gospel! Fuji níkan ni ‘beat’ tó jẹ́ àṣà wa, ‘Highlife’ kìí ṣe tiwa'
Bakan naa lo tun sọ pe, oun ko nilo lati si awọn ẹya ara oun kan silẹ, kawọn eeyan to mọ pe arẹwa ni oun nitori oun funra oun gan mọ pe oun gangan ni ẹwa.
Allyson fi kun pe oun kọkọ maa n ronu jinlẹ lori ipa ti orin ti oun fẹ gbe jade yoo ni lori ẹni to ba gbọ orin naa.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Mo bá Obasanjo ṣiṣẹ́pọ̀ gẹ́gẹ́ bí ológun àti nínú oko, wo ìdí tí ẹ̀mí rẹ̀ fi gùn - Olórin Amona tete bo
- Bola Are kẹnu bọ ọ̀rọ̀ lórí àwọn èdè orin àti ìhùwàsí àwọn Olórin ẹ̀mí lóde òní
- Màmá mi jẹ́ ọ̀gá akọrin ní ṣọ́ọ̀ṣì C&S ní Ile Ife, níbẹ̀ ni mo ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ- Bisi Alawiye••
- Rádaràda lẹ̀yin olórin ẹ̀mí tẹ́ẹ̀ ń ṣí ara sílẹ̀, tún kó elégbè mẹ́rin kó máa túmọ̀ ọ̀rọ̀ onílù - Senwele Jesu
- Orin ayé yàtọ̀ sí orin ẹ̀mí, ẹ máṣe dà wọ́n papọ̀ - Omije Oju mi
- O kú ogun àjàyé Tope Alabi, odò Jodani lo ṣẹ̀ṣẹ̀ là kọjà yìí o! Àmọ́ rántí pé ... - Mike Bamiloye•