Bisi Alawiye Aluko: Akọrin ẹ̀mí Bisi Alawiye ní àánú Ọlọ́run ló sọ òun di akọrin
Bisi Alawiye Aluko ni oun ni itan ki oun to tan, o ni ẹni ti ko ba ni itan ki o tan tan ko ni pẹ to maa fi tan.
O ni ju gbogbo rẹ lọ, aye ọpẹ yọ lori irinajo orin ẹmi ti oun n kọ.
''Awa olorin ẹmi lawọn eeyan n kan bayii, wọn o ka bibeli mọ, nitori naa a gbọdọ kiyesi ara
- Wo akọrin Highlife kan tó ń kọrin bíi Lagbaja
- Wo ìgbésẹ tí Sunday Igboho fẹ́ gbé báyìí lórí àwọn agbẹjọ́rò Cotonou tó ní wón ń gba N4m sí N3m lọ́wọ́ òun
- Ọwọ́ tẹ afurasí bàbá ẹni ọdún 64 tó fi ìpá bá ọmọ ọdún méjì lòpọ̀
- Àjọ DSS fi ẹ̀sùn ìgbésùnmọ̀mí kan olùrànlọ́wọ́ Sunday Igboho méjì tó kù sí àhámọ́
- Bí mo bá fún obìnrin lóyún báyìí, mi ò ní kọ oyún náà, ṣùgbọ́n… - Bobrisky
- Sunday Igboho ní ₦4m sí ₦3m ni ìkọ̀ọ̀kan amòfin mẹ́wàá ní Cotonou gbà láì dènà kí òun má lọ sẹ́wọ̀n
Awa akọrin naa gbọdọ kopa ti wa lori ọrọ orilẹede Naijiria.
A gbọdọ fọwọ sowọ pọ pẹlu ijọba Naijiria
Ọga akọrin ni mama mi ni ṣọọṣi Kerubu ati Serafu ni Ile Ife, ibẹ ni orin ti maa n wu emi naa lati kọ.
Mo maa tẹ le mama mi lọ si ile ijọsin nigba naa,'' Bisi Alawiye lo ṣalaye bẹẹ.