Man gunned in the mouth: Peter Omotoye ní ìbọn nínú ẹnu yìí yí ìgbé ayé òun padà pátápátá
Lasiko ti awọn agbebọn kan dede n ṣọṣẹ ni Alagba Peter Omotoye dede ṣalabapade ibọn ojiji ninu ẹnu rẹ.
Ọmọ Alagba Peter ṣalaye pe ọjọ karundinlọgbọn oṣu kẹta ọdun 2013 ni iṣẹlẹ buruku yii ṣẹlẹ nigba ti baba wa ni oko rẹ to wa lagbegbe ọna marosẹ to lọ si Ibadan.
"Bí wọn ṣe jade si oju ọna ni awọn agbebọn jade si wọn ti wọn si yinbọn ba wọn, ẹnu lo bọ si".
Alagba Peter ti ko lee fi ẹnu rẹ sọrọ lati igba naa, ti ko si lee dede jẹun mọ́ tabi mi eemi daadaa ni ikọlu ọhun ti yi gbogbo igbe aye oun ati mọlẹbi rẹ pada.
- Ẹ fi Sunday Ìgbòho sílẹ, ǹkan tí ìjọba Nàìjíríà bàjẹ́ ló ń gbìyànjú àti túnṣé; Ìjọba àpapọ̀ ní láti tọrọ àforíjì lọ́wọ́ rẹ̀ - Wole Soyinka
- Yomi Fabiyi ṣe fíìmù lórí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha, Iyabo ló dá lé lórí
- Wo àwọn nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Yomi Alliyu, agbẹjọ́rò fún Sunday Igboho tó kọ lẹ́tà sí ìjọba
- Wo ohun tó yẹ kí o ṣe sí ojú abẹ́ rẹ, ''vagina'' lẹ́yìn ìbálòpọ̀
- Sunday Igboho kọ̀wé sí ìjọba àpapọ̀, o ní dandan kí wọn sàn owó gbà má bínú ₦500m
- Mo ti yọ'wọ́ lọ́rọ̀ òṣèlú Nàìjíríà, tẹ́ẹ bá ń gbọ́ pé Obasanjo dá ẹgbẹ́ òṣèlú sílẹ̀, "ẹyẹẹ̀ mi kọ́"!
- Tá ló yọ fíímù Yomi Fabiyi ''Oko Iyabo'' kúrò lójú Youtube, Instagram?
Iyawo rẹ sọ bi o ṣe ya gbogbo wọn lẹnu nigba ti awọn oṣiṣẹ ileewosan pe wọn pe ki wọn maa bọ.
Ọmọ naa ni awọn kọ́kọ́ lo oṣu mẹ́ta nileewosan nigba to ṣẹlẹ, koda o ni "oriṣiriṣi nkan lawọn ti ta fun itọju ẹnu baba wọn.
"Ayẹwo CT Scan ti a ṣe ni Ile Ife fihan pe ẹnu ati ahọn ni ibọn naa bajẹ ati pe dokita ni ida mẹta ahọn wọn lo ti bajẹ patapata".
Ọmọ naa ni gbogbo ounjẹ lawọn n fi ẹrọ lọ ko di olomi ki o to lee fi paipu rọba ti wọn gbe si i nimu jẹun tabi lo oogun.
- Ọlọ́pàá ''Area H'' ní bí a bá pẹ́ jù níwájú àgọ́ àwọn, ìbọn làwọn yóò fi fọ́ wa lẹ́sẹ̀ -Iya Jumoke
- Ẹmí sùn n'Ibadan bí ọkọ tó kó afẹ́fẹ́ gáàsì ṣe ṣìnà lọ kọlu àwọn èèyàn
- Ọkọ̀ òfurufú ọmọ ogun já lulẹ̀ èèyàn 92 ló wà nínú rẹ̀
- Ẹ mú "Candle" wá síbi ètò ìsínkú Wòlíì TB Joshua tí yóò bẹ̀rẹ̀ lọ́la - Ìjọ Synagogue
- Ṣé ẹ ti gbọ́ nípa òkú gbígbẹ́ tí wọ́n ṣì bá oyún nínú rẹ̀?



