Akungba Suicide: Ẹbí, ọ̀rẹ́ àti ọ̀gá iléẹ̀kọ́ sọ̀rọ̀ lórí irú èèyàn tí Feranmi Fasunle jẹ́
BBC Yoruba fẹsẹ kan ile ẹkọ fasiti Adekunle Ajasin nilu Akungba Akoko lati mọ ohun to pa akẹkọọ kan, Feranmi Fasunle laipẹ yii.
Bẹẹ ba gbagbe, Feranmi naa lo gbe oogun oloro jẹ, to si gba ibẹ re ọrun lọsan gangan.
Nigba ti wọn n ba BBC Yoruba sọrọ, awọn ọrẹ, ẹbi ati ọga ileẹkọ naa sọ pe atunbi pọnnpele ni oloogbe naa, to si maa n waasu Jesu kiri.
Koda, ọkan lara awọn to ba wa sọrọ ni oun lo waasu Jesu fun oun, ti oun fi di atunbi.
- Aishat Lola mu pako-pako gba 'bẹ̀ kú - Ọlọ́pàá
- Ọkùnrin kan "lu ìyàwó rẹ̀ pa" nítorí ó lọ síbi ayẹyẹ ìsọmọlórúkọ
- Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọdún mẹ́sàn ká lẹ́yìn tí ọkọ fi ẹ̀sùn olè kan ìyàwó
- ‘DJXgee lọ sòde eré lọ́jọ́ ọdún tuntun láìmọ̀ pé yóò gbẹ̀mí ara rẹ̀’
- Ẹ fura, iyọ̀ onímájèlé tó dóde ti gbẹ̀mí èèyàn méje!
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ní ààdọ́ta ọ̀dọ́ kú lẹ́yìn àpèjẹ tí ọmọ Yahoo kan ṣe l'Akute?
- Mò ń tọ̀ s'ára ni mo fi gba ara à mi l'óko ẹrú ní Oman
Bẹẹ ni wọn sẹ lori ahesọ ọrọ kan to ni akẹkọọ naa gbe majele jẹ nitori ọkunrin to ja silẹ ni.
Wọn fikun pe bi o tilẹ jẹ pe ko si ẹni to mọ idi ti Feranmi fi mu majele yii, sibẹ, awọn mọ pe kii se nitori ọkunrin lo fi se bẹẹ tori awọn ko ri lẹyin ọkunrin kankan ri.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wón ti fi Baba Ijesha, Olanrewaju Omiyinka tí wọ́n fẹ̀sùn ìbálòpọ̀ kan silẹ̀
- "Sunday Igboho kò fí lààkáyé kún ìjìjàgbara rẹ̀ nípa àtakò sí ìbò 2023"
- Mò ń wá olè tó jí nńkan ní ọọ́físì mi, ẹ̀bùn owó iyebíye rèé - Afeez Eniola
- Ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ìlú Modakeke àti Ile Ife
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ni Baba Ijesha ti jáde ní àhámọ́ ọlọ́pàá?
- Ìròyìn òfegè táwọn èèyàn ń gbé kiri lórí ìjà Israel àti Palestine rèé
- Ohun tí àwon Gómìnà egbẹ́ òsèlú PDP fenukò lé lórí rèé nílùú Ibadan
- Nǹkan dé o! Àwọn àgbébọn tún yìnbọn pa ọlọ́pàá méjì lẹ́nu iṣẹ́, wọ́n dáná sun àgọ́ ọlọ́pàá
Amọ ohun to sokunkun niwaju eniyan, kedere ni niwaju Ọlọrun Ọba.




