Nollywood Round up: Lizzy Anjọnrin fẹ̀si fáwọn agbọ́yì-sọ̀yí lórí ìgbéyàwó rẹ̀, Madam Sajẹ dasójú ilé iṣẹ́ àti àwọn ǹkan míràn tó ṣẹlẹ̀ lágbo tíátà lọ́sẹ̀ yìí

Nollywood

Oríṣun àwòrán, others

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 4

Lara awọn iroyin to migboro titi lagbo oṣere tiata Yoruba lọsẹ yii ni bi awọn kan ṣe n ṣe ọjọ ibi lawọn mii n ṣe igbeyawo.

Ki a ma deena pẹnu rara, diẹ re lara awọn iṣẹlẹ to jẹyọ nigbesi aye awọn oṣere tiata Yoruba loṣu yii ree.

Gẹgẹ bi ohun to sọ, oun ati ololufẹ rẹ ọhu ti n bara wọn bọ lati nnkan bi ọdun mẹrinla gbako.

Bimbo Oshin

Ọjọ kẹrinlelogun oṣu keje ọdun 1971 ni wọn bi Bimbo Oshin, agbaọjẹ si ni ninu iṣẹ tiata.

Pupọ ninu awọn ojugba rẹ ninu iṣẹ tiata Yoruba lo n kii ni mẹsan an mẹwaa lọjọ to n ṣe ayẹyẹ ọjọ ibi ọhun, koda ọgbẹni kan fi orin aladun kan sọri rẹ.

Bimbo Oshin se ọjọ ibi

Oríṣun àwòrán, Bimbo Oshin

Bakan naa ni ileeṣẹ kan yaa lẹnu pẹlu ẹbun bantabanta lọjọ naa.

Skip Instagram post, 1
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 1

Doris Simeon

Ọjọ meji ṣaaju ọjọ ibi Bimbọ Oshinn ni gbajugbaja oṣere miran, Doris Simeon ṣe ọjọ ibi.

Oriṣiriṣi aworan to dun n wo loju ni Doris ko si oju opo Instagram rẹ lọjọ naa to pẹ ẹni ọdun mọkanlelọgbọn loke eepẹ.

Pupọ ninu awọn agba ọjẹ ninu awọn oṣere ẹgbẹ rẹ atawọn amuludun miran lo n kii ni mẹsan an mẹwaa.

Doris N se ọjọ ibi

Oríṣun àwòrán, Doris_Simeon

Àkọlé fídíò, Working religious women: Ẹ̀lẹ́hàá kìí ṣe ọ̀lẹ- Aminat Adegoke

Lara wọn ni Dayo Adeneye, Foluke Daramola, atawọn eeyan Kunle Afod, atawọn eeyan jankan jankan miran.

Skip Instagram post, 2
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 2

Mide Martins

Mide Martins

Oríṣun àwòrán, Mymidemartins

Laarin ọsẹ yii kan naa ni Mide Funmi Martins tẹsiwaju ninu fiimu kan ti wọn ya lọwọ, "Enu mi."

Ọkọ rẹ Afeez Olayiwola Abiodun ti ọpọ eeyan mọ si Afeez owo lo n dari fiimu naa.

Lara awọn to n kopa ninu fiimu ọhun ni Mide Funmi Martins funra rẹ, Omotayo Amokade ti ọpọ mọ si Ijebu, atawọn oṣere n la mii lo kopa ninu ere ọhun.

Adebimpe Oyebade àti Lateef Adedimeji

Adebimpe ati Lateef

Bí ọ̀ṣẹ méjì sẹ́yìn ni òkìkí kan nígbà ti àwòràn kan fẹ́ fa orí ayélujára ya lórí pé bóya Adebimpe àti Adedimeji ṣe ìgbéyàwó.

Sùgbọ́n gbogbo ǹkan to wà nínú ìgò náà tó ń jẹ́ jìínì ti fójú hàn báyìí nígbà ti Adebimpe kédé pé, ọbẹ̀ ti àwọn ń se ti jina tan

O ní àkọlé eré ti àwọn ṣe pọ̀ náà ni "Resentment''

Sinima Agbelewo

Oríṣun àwòrán, Adebimpe

Ọ̀pọ̀ ọmọ Nàìjíríà ló ti ń ṣe sàdánkáta kare sí wọ́n lóri sinimọ agbélé wò náà.

Fausat Balogun àti Laide Bakare

Madam Saje ati Laide Bakare

Nínú ọ̀ṣẹ̀ yìí ìṣẹ̀lẹ̀ mánigbàgbé ni bi Fausat Balogun ti gbogbo ènìyàn mọ si Madam Ṣajẹ náà sé tọwabọ iwé àdéhun pẹ̀lú ilé iṣẹ́ kan.

Madam Ṣajẹ yóò ma sojú wọn ilé iṣẹ kan ti wọ́n ntale talẹ.

Skip Instagram post, 3
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 3

Ọ̀pọ̀ àwọn olólufẹ gbájúgbaja eléré tíátà náà ló ti ń baa dáwọ ìdúnu ní gbogbo rí ayélujára

Skip Instagram post, 4
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 4

Ẹ̀wẹ́ lọ́jọ́ kan náà ni Laide Bakare náà tọwọ́ bọ ìwé àdéhùn pẹ̀lú ilé iṣẹ́ tó mójútó ilé àti ilẹ̀ rírì nílùú Ibadan láti jẹ asojú ilé iṣẹ́ náà.

Ìdùnnú subú layọ̀ láàrìn àwọn òṣèré tíátà nínú ọṣẹ yìí. Awọn olólùfẹ́ wọ́n nínú eré tíàta àti láwùjọ ló ti n bá àwọn gbájúgbajà òṣèré méjèèjì dáwọ idùnú.

Skip Instagram post, 5
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 5

Lizzy Anjorin

Lizzy ati ọkọ rẹ

Oríṣun àwòrán, Lizzyanjorin/instagram

Tí ẹ o bá gbàgbé Lizzy Anjonrin ṣe ìgbéyawó laipẹ yìí, to sí fí àwọn fóto ìgbéyàwó náà síta lórí àtẹjíṣẹ rẹ̀ ni ọṣẹ̀ tó kójá òdé yìí.

Sùgbọ́n ó ìyawó ọ̀lẹ̀lé ti pada sórí ìkànsiraẹni Instagram láti fún awọn agbọ́yì sọ̀yí lésì lórí ǹkan ti wọ́n ń sọ nipa ọkọ rẹ̀.

Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, Lizzy Anjonrin to ti di Abilekọ Lawal ni kí gbogbo àwọn agbọ́yì sọ̀yí lọ gbọ dáada pé ọkọ oun ko fẹ́ ìyàwó mẹrin ko to fi oun ṣaya.

Lizzy sọ èyí di mímọ lójú òpó Twiiter rẹ̀ pé ìdí ti òun fi jáde fẹ̀sì sí ọ̀rọ̀ náà nitóri ìrú ipò ti òun dìmú láwùjọ.

Ǹkan to sọ rèé

Skip Instagram post, 6
Allow Instagram content?

This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of Instagram post, 6