Bolatito aya Timothy Adegoke bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ ni ọdún kan lẹ́yìn ikú ọkọ rẹ̀
Adájọ ti pada dájọ́ iku nipa yiyẹgi fun ni fun Adedopyin Rahaman ati awon oṣiṣẹ rẹ meji lori iku Timothy AdegokeÌdájọ́ ikú nípa yíyẹgí fún Oloye Adedoyin ni Adájọ́ kéde ǹsìyí láti iléẹjọ́ gíga Osogbo
Mo ti gba ọrọ Bibeli gbọ pé ki a maa dupẹ ninu ohun gbogbo- Bolatito Adegoke
Ọdun kan ti pe léyin ti Timothy Oluwadamilare Adegoken ku ti ọwọ awọn ọlọpaa si tẹ awọn afurasi kan ni ilu Ile Ife ni ipinlẹ Osun Ẹ̀jọ́ àtí ìwádìí ikú Timothy Adegoke ti kúró lọ́dọ̀ọ wa nípinlẹ̀ Osun- Agbẹnusọ Ọlọ́pàá Oṣun
Arabinrin Bolatito Adegoke to jẹ aya oloogbe ṣalaye awọn ipenija ti oun ti koju lẹyin iku ọkọ rẹ lori ọmọ ati ara rẹ."Ọlọ́pàá ló pe mí láti wá gbé òkú Timothy Adegoke lẹ́sẹ̀ títì"
O fi ẹmi imoore han fun ẹbi, ara ati ojulumọ pe wọn ku aduroti oun lẹyin ọdun kan ti awọn afurasi kan se iku pa ọkọ rẹ.Lẹ́yìn ọdún kàn, ǹjẹ́ òtítọ́ ti faráhàn lórí ikú Timothy Adegoke-
- Adedoyin àti afurasí yókù ní àwọn kó jẹ̀bi ẹ̀sùn ípànìyàn tí iléẹjọ́ fí kàn wọn
- Àlàyé lórí ìtumọ̀ ‘Subsidy’ àti ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ tí ìjọba bá yọ ‘Subsidy lórí epo
- Timothy Adegoke: Ìyàwó Timothy Adegoke jẹ́rìí nípa ọkọ rẹ̀ nílé ẹjọ́, gbọ́ nípa ìjà tó jà fún ọkọ̀ rẹ̀
- Iléẹjọ́ sún ìgbẹ́jọ́ lórí ikú Timothy Adegoke síwájú, Wo ohun tó fàá....
- Mọ̀ síi nípa ewu tó rọ̀ mọ́ níní ìbálòpọ̀ lásìkò ìlóyún lórí ètò Sé lóòtọ́ ní BBC
- Kí ló ń dá ọlọ́pàá dúró láti gbé Rahmon Adedoyin àti ọmọ rẹ̀ relé ẹjọ́ lórí ikú Timothy Adegoke?
- Ta ló ń dá ìwé àṣẹ Falana láti sójú ìdílé Adegoke dúró? Ohun táa mọ̀ rèé
- Femi Falana kò gba kọ́bọ̀ fún ìgbẹ́jọ́ Timothy Adegoke àmọ́ aráàlú ń dáwó jọ - Ẹ̀gbọ́n olóògbé


