ASUU Strike effect: Gbogbo àwon tó n ṣiṣẹ́ nítorí ileẹ̀kọ́ sọ̀rọ̀ lórí ìṣòro wọn látìgbà ti ẹgbẹ́ Oluko ti daṣẹ silẹ
Wo díẹ̀ lara nkan to ti ṣẹlẹ si awọn akẹkọọ leyin ti ẹgbẹ Oluko ASUU ti daṣẹ silẹ.Ó yẹ kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbé àjọ̀ ASUU lọ sílé ẹjọ́ fún ìfàkókò ẹni ṣòfò- Mínístà Adamu
Egbẹ osise ti wọn jẹ olukọ Fasiti kaakiri Naijiria lo bẹrẹ iyanṣẹlodi lati nkan bii oṣu mẹfa sẹyin bayii.
BBC jade lọ si igboro Federal University of Agriculture to wa ni Abeokuta nipinle Ogun lati lọ wo bi nkan ṣe n lọ lẹyin iyanṣẹlodi ẹgbẹ olukọ Fasiti, ASUU.
- Ìròyìn ẹlẹ́jẹ̀ ni pé mo buwọ́lu Tinubu fún ipò Ààrẹ -Obasanjo
- Lẹ́yìn ọdún mẹ́tàlá ìjọba àpapọ̀ yan ìgbímọ̀ ẹlẹ́ni méje míì láti jíròrò pẹ̀lú ASUU lórí àdéhùn 2009
- Ṣé ó ṣeéṣe kí ẹgbẹ́ ASUU fi òpín sí ìyànṣẹ́lódì rẹ̀ lọ́jọ́ Aje?
- Gbèsè àti Kérésì elébi ni ìyansẹ́lódì ASUU bádé fún wa - Òǹtàjà ní fásitì
- Wo àwọn iṣẹ́ méje tí o lè kọ́ láàrín oṣù mẹ́ta ti ASUU da iṣẹ́ sílẹ̀

Lara awọn ti BBC ba sọrọ ni Arabinrin Akinfenwa to n ta ọja, Arabinrin Bilikis Aremu to jẹ alatẹ, Arabinrin Esther Adeboye to n ta ewebẹ, Olorungbebẹ Lawal awọn awakọ, Hakeem Ogunsola to jẹ baba onile naa royin ohun ti oju gbogbo wọn ti ri lati igba ti ASUU ti daṣẹ sile bayii.

Bakan naa ni Ogbeni Osunfowora Abdulhazeem, Alagba Messai JP, ati Aderonke royin inira ati gbese to ti de ba gbogbo awọn olutaja ni agbegbe ile ẹkọ giga bayii.
Awọn akẹkọọ bii Pamilerin, Olashile, Olusanya Taiwo ati awọn mii naa ba BBC sọrọ lori ohun to n ṣẹlẹ si wọn bayii pẹlu ẹbẹ pe ki ijoba Naijiria jọwọ da ẹgbẹ olukọ lohun.
- Báwo ni èròjà Fáítámì D ṣe ń dáàbò bo àgọ́ ara wa?
- Ṣé lóòtọ́ ni àwọn agbébọn ṣekúpa èèkàn ẹgbẹ̀ òṣèlú APC l’Osun-
- Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ bàbá ẹni ọdún 49 tó fún ọmọ ara rẹ̀ lóyún ní ìpínlẹ̀ Ogun
- Ta ló kọlu ìyàwó gómìnà, tó fi di gbódónróṣọ láàrín ìjọba àti ẹgbẹ́ òṣèlú PDP l'Osun
- Ṣé lóòtọ́ ni àwọn ọmọ ogun Naijiria àti Niger gba ogúnlọ́gọ̀ ìbọn lọ́wọ́ àwọn jàndùkú-
- Bí ìjọba bá tẹ̀síwájú láti máa yan ọba, ìlú kò lè tòrò láíláí - Àwọn oníṣẹ̀se
- Ẹ ṣọ́ra o, agbénipajayé kan wà nígboro tó ń pa tọ̀dọ́-tarúgbó báyìí - Ọlọ́pàá