Dapo Abiodun yombo Bola Tinubu nibi ètò fún àwọn Oníṣẹ ọwọ́ ní Abeokuta
Awọn Oba ile Yoruba kan ni pe wọn ti bẹrẹ igbesẹ to maa mu ẹnu iran Yoruba kò sí ojú kan ninu ididbo 2023Àlàyé rèé lórí ohun tó fa ìpàdé tó ń wáyé lọ́wọ́ láàrín Obasanjo, Tinubu, àtawọn ọbalayé ilẹ̀ Yorùbá l'Abeokuta
Ni ana, ọjọ ketadinlogun, oṣu kẹjọ, ọdun 2022 ni ọpọ awọn Ori Ade ilẹ Yoruba pe ipade laarin Bola Tinubu ati Olusegun Obasanjo to jẹ aarẹ nigba kan ri ni Naijiria.
Oba kan ti ko fe ki BBC darukọ rẹ ṣalaye fun BBC pe ki iran Yoruba le tọ si oju kan naa lo ṣokunfa ipade yii.
Leyin ipade naa ni wọn lọ si papa isere MKO Abiola to wa ni Kutọ nilu Abeokuta to je olu ilu ipinle Ogun ni guusu Iwoo oorun Naijiria.
- Egbẹ́ òṣìṣẹ́ iná mọ̀nàmọ́na ti wọ́gilé ìyanṣẹ́lódì wọn lẹ́yìn tíjọba ṣèlérí pé..-
- Ọmọ mẹ́rin bómilọ níbùdó ìgbafẹ́ etí òkun kan l'Eko
- Àlàyé rèé lórí ohun tó fa ìpàdé tó ń wáyé lọ́wọ́ láàrín Obasanjo, Tinubu, àtawọn ọbalayé ilẹ̀ Yorùbá l'Abeokuta
- Irú ọmọ wo ní Yorùbá ń pè ní Olúgbódi?
- Babagana olùdámọ̀ràn lórí ètò aàbò Nàìjírà, kọ̀wé fipò sílẹ̀ tàbí kí Buhari da ẹ dúró- Arewa

Dapo Abiodun to je gomina ipinle Ogun fun ẹgbẹ awọn Osise nibẹ ni ọkọ bọọsi akero kan pe oun mu lara ileri to ṣe fawon oniṣẹ ọwọ ṣẹ.

Leyin naa lo ṣafihan Bola Tinubu to n dije lẹgbẹ oṣelu APC sipo aare Naijiria lọdun to m bo.

Dapo Abiodun ni pe Tinubu lo kan bayii.
Ni ilu Abeokuta ni ipinle Ogun ni awon Ori Ade ti mu oju aje ko onisọ lati bẹrẹ igbesẹ ti yoo jẹ ki ẹnu iran Yoruba ko papọ.

- Irọ́ ni wọ́n pa mọ́ mi, mi ò gbé Atiku lọ ilé ẹjọ́ – Wike
- Ó ṣeéṣe kí Salman Rushdie pàdánù ojú kàn nítorí ọ̀bẹ tí wọ́n gún un lọ́rùn - Agbẹnusọ
- Ń kó gbá àádọ́ta bílíọ́nù lóṣooṣù lọ́wọ́ Ambode – Tinubu
- Wo bí tọkọtaya ṣe fi ìmọ̀ ìṣìrò jẹ tẹ́tẹ́ $26m àti ìdíje oríire míì l‘Amẹrika
- ‘Muslim Muslim Ticket’ tí APC ṣekò ní ìtẹ́wọ́gbà - Kukah
- Àwa adarí tiraka láti mú ìbáṣepọ̀ àláfíà bá Nàíjíríà àmọ́ ìyapa ẹ̀sìn àti ẹ̀yà ṣèdíwọ́ - IBB