Osun spider man: Mo ń ṣe ìtanijí láti gbógunti ìdọ̀tí láwùjọ ló sún mi dé ìdí 'Spider-man'
Mo korira idọti pupọ- Jonathan Olakunle Olanlokun
Ooru maa n mu mi nitootọ ti mo ba wa ninu aṣọ alantakun mi- Jonathan
Ariwo ọkunrin alantakun to n fọ ilu Osogbo mọ nipinlẹ Osun ni Iwo oorun guusu Naijiria ni aye n pariwo lori ayelujara bayii.
Eyi lo mu ki Abeeb Alawiye to jẹ ọkan lara awọn akọroyin BBC Yoruba lọ wa a kan ni Osogbo. ẹwo ohun ti wọn ba bọ ninu fọnran fidio yii.
- Wo ìdí tí Oyomesi ṣe jẹ́ kí wọ́n kírun sí ara Oba Lamidi Adeyemi ṣáájú ètò ìsìnkú ìṣẹ̀ṣe
- Bàbá mi ni 'Welder' Uncle mi ní 'Coiler' ṣùgbọ́n mo padà fi ṣoríire- Afusat Adeniyi
- Buhari lo fi kún ìṣòro Nàìjíríà ní ìlọ́po méjì, o ba ilẹ̀ jẹ́ gidi- Ojọ̀gbọ́n Banji Akitoye
- Bí Jesu kò bá jíǹde, asán ni ìgbàgbọ́ Krìstẹ́ní kò bá jẹ́ - Olórí ìjọ Celestial lágbàyéé
- "Aṣọ ni mo fẹ́ máa tà tẹ́lẹ̀, ọkọ́ mi ló ní kí ń kọ́ iṣẹ́ Káfíńtà àmọ́ ń kò kábàmọ́ọ̀"
- 'Wọ́n jí pè mi pé ọmọ mi bímọ-dákú àmọ́ bí mo ṣe débẹ̀, àt'òkú ọmọ mi, àt'òkú ọmọ rẹ̀ ni mo bá ní Mọ́ṣúárì'

Bawo ni 'Spider Man'se bẹrẹ iṣẹ naa?
Ogbeni Jonathan Olakunle Olanlokun salaye fun BBC Yoruba pe oṣu kejila, ọdun 2020 ni oun bẹrẹ si ni wọ aṣọ naa.
O salaye pe orilẹ-ede America ni oun ti wa aṣọ naa kan ko too de si Naijiria fun oun.
O ni ìran lati bẹrẹ itaniji lati gbogun ti iwa idọti ni o sun oun de idi fifi aṣọ alantakun gba opopona ati adugbo ati ọja kaakiri Osogbo.
- Indonesia fòfin de títa epo pupa rẹ̀ sílẹ̀ òkèèrè, wo ipa tí yóò ní lára Naijiria àti Africa lápapọ̀
- Ìgbẹ́jọ́ Ilànà Ọmọ oodua àti Náìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ nílé ẹjọ́ ní Ekiti
- Mo ti 'ùnfollow' ẹ lórí 'social media'; Ọlọ́run a ṣe idajọ fún ẹyin méjèèjì- Iyawo Yul-Edochie
- 'Ẹran ẹtu ni mo yìnbọn sí, àmọ́ òkú ìmáàmù ni mo bá nígbà tí mo fẹ́ gbe e'
- Kìí ṣe nǹkan abàmì bí Alaafin, Soun àti Olubadan ṣe papòdà lèralèra - Elebuibon
- Látàri ìjà Russia àti Ukraine, Bí a ṣe fẹ́ dènà ìyàn oúnjẹ ní Naijiria rè é- Buhari
- Wo bí ètò Orò Ìje Oba Lamidi Adeyemi to wàjà ṣe lọ ní Oyo
- Ọlọ́pàá Eko kéde orúkọ ọlọ́pàá tó ṣíná ìbọn bolẹ̀ nílé ọtí, téèyàn méjì fi kú