Kwara Waka: Orin Wákà la fi ń ṣe Wáàsí, o tó ọdún 70 tí mo tí bẹ̀rẹ̀ láìnáání èébú tí ọ̀pọ̀ ń bú wa- Alhaja Rukayat Batimoluwasi

Àkọlé fídíò, Alhaja Rukayat Batimoluwasi Oniwaka: Orin Wákà la fi ń ṣe Wáàsí, o tó ọdún 70 tí mo tí bẹ̀

Kò sẹni to le yi ọna ẹda pada laye- Alhaja Batimoluwasi

Alhaja Rukayat Batimoluwasi sọ nipa bi o ṣe bẹrẹ ere waka ni ilu llorin saaju igba ọwọn iyọ ati ogun Ojukwu.

O menuba iṣẹ itunnu, iṣẹ koriya, ati iṣẹ ironilọkan le ati iwaasu ti oun ati awọn ọmọ ẹgbẹ rẹ n fi ere Waka ṣe.

Alhaja Rukayat

Alhaja Rukayat slaye nipa awọn eeyna to le ni mokandinlogbon ti o ti fi iṣẹ Waka ran ni Mecca.

O sọ nipa oore to pọ ti Olorun ti ṣe fun oun lẹnu iṣẹ Waka yii.

Keyframe #1

Alhaja Rukayat gbb awọn ọdọ nimọran lati maa naani iṣoro to n koju wọn lẹnu iṣẹ ti ori ran wọn nitori pe ayọ lo maa gbẹyin rẹ fun wọn.

O ṣalye pe nitori owó ni wọn ṣe n fun ọpọ ni ami ẹyẹ Áward'ni asiko yii sugbọn atẹlẹwọ ẹni kii tan ni jẹ.

Waka