Magaret Jimoh: Èrè díẹ̀ ti tó mi níbi oúnjẹ ti mò ń tà- Maggie Rice

Àkọlé fídíò, Magaret Jimoh: Èrè díẹ̀ ti tó mi níbi oúnjẹ ti mò ń tà- Maggie Rice

Ojú kòkòrò wa ti pọ̀ jù, kìí ṣe ìjọba nìkan kọ́ ni ìṣòro Nàìjíríà- Maggi Oní ìrẹ́sì àyi ẹran N10

Arabinrin Magaret Jimoh to n ta ounjẹ ni Ijemo, Odo- Aje ni Ado Ekitit ni ipinlẹ ekiti ba BBC sọrọ ilẹ kun.

Maggi Rice ni lati ọdun 1984 ni oun ti n ta ounjẹ ni owo perete.

Koda o ni ko pẹ ti oun sọ irẹsi elewe kan di naira mẹwaa ti ẹran naa di naira mẹwaa.

Iresi

Maggi Rice mẹnuba koko pe ẹlẹyinju aanu to ni itẹlọrun ni oun.

O ni ere kekere ti to oun lati jẹ ki ebi ma pa ara ilu nitori igboro ko rẹrin ni Naijiria.

Iresi

Margaret mẹnuba awọn nakn ti o ti gbe ṣe nidi irẹsi tita yii

O gba awọn ontaja nimọran lati ma ni ojukokoro ati pe ki ere kekere maa tẹ onikaluku lọrun nitori ilu le.