Trade by Barter, Rivers: Mọ̀ síi nípa ọjà ní Esuk Mba, níbití o ti lè fi iṣu gba edé, epo àti ǹkan míì
Wo diẹ lara aleebu ati anfani irufẹ ọja yii ni Naijiria.
Ojọ Abamẹta nikan ni wọn ma n na ọja yii ni ilu Esuk Mba ni ipinlẹ Rivers ni aarin guugu-guusu Naijiria.
- Ọgbà wèrè àti ilé aṣẹ́wó nilé ẹni tí kò lówó tó tún fẹ́ ìyàwó mẹ́rin- Sheik Akewugbagold
- Àtẹ̀jádé ìjọba apapọ̀ lórí ọ̀rọ̀ Pantami fihàn pé wọ́n ń káànú ìgbésùnmọ̀nmí- PDP
- Àwọn aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ EKSU ti ní kí wọ́n gbé ilé ẹ̀kọ́ náà tì pa!
- Lóòtọ́ ni pé nínú àwọn ọmọ Olóyè wà nínú ẹgbẹ́ tó ń da Ikorodu rú- Oba Ganiyu Aderibigbe
- Ikọlù agbébọn tó jó ilé Gómìnà ìpínlẹ̀ lọ́wọ́ òṣèlú nínú-Ìjọba Imo
- Ǹkan dé o! Àwọn jàndùkú tún yìnbọn pa ọlọ́pàá méje lẹ́nu iṣẹ́, wọ́n dáná sun ọkọ̀ wọn
Kini a n pe ni paṣipaarọ ọja?
Irufẹ nkan wo ni ẹ le fi paarọ ara wọn?
Kini aleebu ati anfani ti ẹ le ri nibẹ?
Idahun awọn ibeere yii wa ninu fọnran ifọrọwanilenuwo ti BBc ṣe si ọja paṣipaarọ yii nipinlẹ Rivers.
- Màálù tí Ojo fẹ́ fi ṣègbeyàwó ló fẹ́ lọ rà tí wọ́n fi pà á, ti wọ́n gé ẹ̀yà ara rẹ̀ ní Kwara
- Ẹjọ́ ń bẹ lọ́run fún gbogbo ẹ̀yin tí kò wàásù fáwọn tó ń tẹ lé yín lórí Instagram àti Facebook- Mike Bamiloye
- Olólùfẹ́ Naira Marley kọ sẹ́nu tírélà nítorí ₦500 tó fẹ́ gbà lọ́wọ́ rẹ̀
- Ẹ gbà mí, Boko Haram ti gba ìjọba ìpínlẹ̀ Yobe mọ́ mi lọ́wọ́ - Gómìnà Buni
- Babaláwo rí ẹ̀wọ̀n he! lẹ́yìn tó ṣe ìwòsàn fún obìnrin pẹ̀lu tábà fínfín, ló bá kú lójijì!
Ofiong Etim Okon, Arit Ekpo, Merit Akon ati Rosemary Achibong to jẹ kọmiṣọnna okoowo ni ipinle Rivers sọrnọ nipa ọja yii ati pataki rẹ laisko yii.
Bẹẹ, eyi tun n ran wa leti pe awọn ọja kan ti wa nitootọ laye atijọ to jẹ pe a kii na owo nibẹ bikoṣe ki a fi ọja ra ọja mii.
- Adunni Olorisa, obìnrin òyìnbó tó di ìyàwó òrìṣà nílẹ̀ Yorùbá títí di ọjọ́ ogbó
- Àwọn Olùkọ́ Yorùbá ní ìpínlẹ̀ Osun ṣe bẹbẹ lórí ètò Akomọlede àti Aṣa lórí BBC
- Mo fẹ́ ìyàwó méjì lọ́jọ́ kan ṣoṣo láti ṣe ju ohun tí bàbá mi gbé ṣe - Uloho Othuko
- Ṣé irúfẹ́ oúnjẹ tí ò ń jẹ́ lè jẹ́ kí o gbádùn ìbálòpọ̀ rẹ síi?
- Pásítọ̀ pín ounjẹ iṣínu àwẹ̀ Ramadan fún àwọn Músùlùmí
- ‘Jí foonu ọkọ rẹ̀ wò, kóo fi ẹ̀wọ̀n jura’